Àwọn ọlọpàá ní ìpínlẹ̀ ọyọ́ ṣe ìpàdé àpérò pẹ̀lú àwọn tọ́rọ̀kàn nibi ètò ààbò ní olú ilé iṣẹ́ ọlọpàá ní Ibadan.
Lára àwọn tó pẹ́ju síbẹ̀ ní asojú DSS, FRSC, NSCDC, àwọn ọga aṣọ́bode àti àwọn akọròyìn.
Èrèdí ìpàdé ọ̀hún ni láti ṣe ìlanilọ́yẹ fún àwọn olùdibò àti àwọn elétò ààbò sáájú ìdìbò tí yóò wáyé lọ́jọ́ Àbámẹ́ta.
Bákan náà ní Ìpinlẹ Kwara
Komisana Ọlọpa ní Ìpínlẹ̀ Kwara, Kayode Egbetokun ní Ọkọ baalu àwọn ọmọ ajọ ológun yóò máa yi de kí rí ní Satide ọjọ́ idibò di pò baalu helicopter tí wọn fí yi de lọ́jọ́ ìdìbò aare ní Ìpínlẹ̀ Kwara.
Egbetokun tó bá àwọn oniroyin sọ ro n'ilu Ilorin ni àjo Ọlọpa àti gbogbo eso abo tí gbaradi láti rí pé eto ìdìbò ọjọ́ Satide wáyé ní ìró wo rò ṣe lábẹ́ ààbò tó gbó pọ.
O ni gbogbo ètò ló tí tó láti rí pé eto ìdìbò náà wáyé ní abẹ àbò tó gbó pọn.
Egbetokun ní gbogbo eso abo àti àwọn ológun tí yóò kó pá nínú ètò ìdíbo náà ni wọ́n ti gbà idani leko tó pé.