You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Ọ̀pọ̀ èèyàn di àwátì lẹ́yìn tí ọkọ̀ ojú omi ńlá kọlù afárá l’Amẹrika

Akojọpọ awọn iṣẹlẹ kaakiri agbaye

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Olumide Owaduge and Olubusola Afolayan

  1. Àlàyé rèé lórí bí òkùnrin kan ṣe pàdánù $2.1m sórí ‘cryptocurency’

  2. Mohbad kò bá má kú, ká ní òun àtàwọn òbí rẹ̀ sá di OPC tàbí sọ fún wa nípa ìdojúkọ rẹ̀ – OPC

  3. Ojú lásán kọ́ ni ọ̀rọ̀ iná tó jó ilé ẹjọ́ tó ga jùlọ, ejò lọ́wọ́ nínú – PDP yarí

  4. Mi ò kàn dédé fún Mide Martins lóyún, bí ìrìnàjò ìfẹ́ wa ṣe bẹ̀rẹ̀ nìyí - Afeez Owo

  5. Ladoja yarí kanlẹ̀ láti ṣàmì ọjọ́ ìbí rẹ̀ bó ṣe pé ẹní ọdún 79 lónìí

  6. Àìsàn onígbá méjì ṣekúpa ènìyàn 84, àwọn 2,860 míì tún lùgbàdì rẹ̀ – NCDC

  7. Iléeṣẹ́ ológun ṣe àwárí ibùdó tàwọn kàn tí n rọ̀ ìbọn ní gúúsù Kaduna

    Ileeṣẹ ologun orileede Naijiria ti kede pe awọn ti ṣeawari ileeṣẹ kan tawọn kan ti n rọ ibọn ni ilu Kafanchan to wa ni ijọba ibilẹ Jamaare ni ipinlẹ Kaduna.

    Atẹjade ti ileeṣẹ ologun fi soju opo wn ni Facebook ṣalaye pe wọn ri ibudo yi lẹyin iwadii ọtẹlẹmuyẹ ọlọsẹ kan gbako eyi to mu ki wọn ṣawari ogbologbo arakunrin kan to n ta ibọn torukọ rẹ n jẹ Napoleon John.

    Wọn sọ pe Napoleon John yi tọwọ tẹ lo mu awọn lọ si ibi to ti n ra ibọn naa eyi to mu ki ọwọ tẹ arakunrin mii to n rọ awọn ibọn orisirisi wọnyi.

    Bakan naa lawọn ologun yi sọ pe ẹni to n ta ibọn yi loun ti wa lẹnu iṣẹ yi o to dun marun un sẹyin.

    O ni lagbegbe Plateau ati Kaduna loun si ti n ṣowo ibọn tita YI.

    Igbiyanju awọn ologun mu ki wọn ṣawari ibọn orisi mejilelogun ninu wọn taa ti ri agbelẹrọ ibọn AK47 meji ati ibọn pelebe meje.

    Awọn to ku ni ibọn ṣahakbula kan ati eleyi to n lo ọta 7.62

    Bẹẹ naa ninu ikọlu ti awọn ọmọ ologun ṣe ni eyi to waye ni ọjọ kejilelogun oṣu Kẹsan an ni abule Adua ni Kafanchan nibi ti wọn ti ri ibọn AK 47 meji gba foonu alagbeka meji aṣọ ọlọpaa meji ati ṣokoto awọn ọmọ ogun to fi mọ awọn nkan miran.

  8. Emefiele kọ̀wé fipò sílẹ̀ bí Cardoso ṣe bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi gómìnà CBN

  9. Kí ló fa wàhálà láàárín Canada àti India?

  10. Wo kókó ọ̀rọ̀ tí Tinubu sọ níbi àpérò àjọ ìṣọ̀kan àgbáyé

  11. Bayowa fèsì padà fún Busola Oke Eleyele

  12. Ọmọ tí ìfun rẹ̀ di àwátì nílé ìwòsàn lẹ́yìn iṣẹ́ abẹ jáde láyé

  13. Òní ló pé ọjọ́ méje tí Mohbad jáde láyé, ẹ wo ibí tí ọ̀rọ̀ dé dúró

  14. Mọ̀ síi nípa àwon Orí Adé Soun tí ìlú Ogbomọṣo tó ti jẹ́ láti ìbẹ̀rẹ̀....

  15. Ṣé lóòótọ̀ ni pé ìdìtẹ̀gbàjọba tún ti wáyé ní Congo?

  16. Mali Burkina Faso àti Niger buwọ́lù ìwé àdéhùn lórí ààbò

    Olori orilẹede Mali ati awọn alamuleti rẹ meji ìyẹn Burkina Faso ati Niger ti fẹnuko lori Ipese aabo lati koju awọn to ba fe gbogun j'awọn lati ita.

    Wọn buwọ́lù adehun yi lọjọ Abamẹta to sì sọ di dandan ki wọn ṣe atilẹyin ologun fún eyikeyi ti o ba nilo iranwọ ologun.

    Olori ìjọba ologun Mali Assimi Goita sọ pé " mo fọwọsi adehun yi pẹlú àwọn olori Burkina Faso ati Niger pẹlu erongba idasilẹ ẹtọ ipese aabo ajumọṣe laarin ará wa"

    Lọwọlọwọ bayii awọn orilẹ-ede mẹtẹẹtaa yi jo n koju idojule lati ọwó ajọ ECOWAS tori pe wọn kò faaye gba ijọba awaarawa.

    Bẹẹ náà ni wọn n koju wahala lati ọdọ agbesunmọmi to ni ajọṣepọ pẹlu Al Qaeda ati Islamic State.

    Ecowas ti ṣaaju halẹ pe awọn yoo lọ ọmọ ogun lati fi da ijọba awaarawa padà ní Niger lẹyìn tàwọn ologun yẹ àga nidi aarẹ Mohammed Bazoum.

    Amọ awọn orilẹ-ede mẹta yi latara adehun ajumọṣe tí wọn buwọ́lù torukọ rẹ n jẹ Liptako-Gourma Charter sọ erongba wọn sì mímọ pe bi ECOWAS ba ṣe bẹẹ awon yóò pawọpọ koju wọn padà.

  17. 'Nítorí à ti lè tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ mi ni mo ṣe lọ ń kọ́ iṣẹ́ irun gígẹ̀'

  18. Lizzy Jay ké gbàjarè pé ẹnìkan fẹ́ máa lò fídíò ìhòhò òun gba owó lọ́wọ́ òun

  19. Àìtẹ̀lé ìlànà òfin la ṣe wó ilé iṣẹ́ tí Gbenga Daniel ń kọ́ ní Ijebu Ode - Ìjọba Ogun

  20. Ìdí rèé tí mo fi wa lórí 'Wheelchair' tí ọ̀pọ̀ èèyàn ṣe ń gbàdúrà fún mi - Saidi Balogun