You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Ọ̀pọ̀ èèyàn di àwátì lẹ́yìn tí ọkọ̀ ojú omi ńlá kọlù afárá l’Amẹrika
Akojọpọ awọn iṣẹlẹ kaakiri agbaye
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Olumide Owaduge and Olubusola Afolayan
Ìjàmbá ọkọ̀ gbẹ̀mí èèyàn kan ní òpópónà márosẹ̀ Eko sí Ibadan
Bùọ̀dá àdúgbò ni Kamo jẹ́ sí mi, ọjọ́ tá a bẹ̀rẹ̀ àwàdà la ra àṣọ àti koto Nepa - Ozain
Ìdúnkookò bẹ̀rẹ̀ láti yọ ààrẹ Amẹ́ríkà, Joe Biden nípò torí ẹ̀sùn tí wọn fi kan ọmọ rẹ̀
Awọn ọmọ ẹgbẹ oselu Republican to wa nile asofin lorilẹede Amẹrika ti kede pe ọjọ akọkọ tawọn yọju sibi ijoko igbimọ oluwadii lati yọ aarẹ Joe Biden nipo, ti seso rere tori awọn lanfaani lati wi awijare tawọn.
Amọ awọn onwoye awọn ẹlẹri tawọn ọmọ ẹgbẹ oselu Republica ko wa sibi ijoko naa wa sekilọ pe ko tii si ẹri to daju nilẹ, ti wọn fi le yọ aarẹ Biden nipo.
Olori ile asoju-sofin nilẹ Amẹrika, Kevin McCarthy wa kede iwadi wọn lori awọn ẹsun ti wọn fi kan ọmọ aarẹ Biden, eyiun Hunter.
Lara awọn ẹsun naa ni pe o lọwọ ninu awọn okoowo ti ko tọ eyi ti aarẹ Biden jẹ ninu anfaani ti okoowo naa mu wa.
Ile ijọba ilẹ Amẹrika si ti sapejuwe igbesẹ iwadi aarẹ Biden yii gẹgẹ bii ‘ete oselu’ lasan.
Iwadi awọn ọmọ ẹgbẹ oselu Republica lo kuna lati se awari ẹri to daju nipa awọn ẹsun ti wọn fi kan aarẹ Biden fun ọpọlọpọ osu.
Idi si ree ti ile asofin fi gbe igbimọ oluwadi naa kalẹ, lati ro awọn asofin lagbara nla labẹ ofin, lati se iwadi awọn ẹsun asemase naa.
Nibi ijoko akọkọ igbimọ oluwadi naa, Hunter Biden, tii se ọmọ aarẹ, mu awọn ọmọ ẹgbẹ Republican lomi.
Awọn ọmọ ẹgbẹ oselu naa si lo fẹsun kan Hunter pe o n ta anfaani pe o sunmọ baba rẹ, tii se aarẹ ilẹ Amẹrika.
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ ọ̀kan lára àwọn afurasí tó ṣekúpa DPO Bako
Ṣé ríró òkú tàbí 'Autopsy' ló dára jùlọ láti tú àṣírí òkú tí wọn bá pa?
Ọmọ aṣofin kan l‘Oyo àti akẹ́kọ̀ọ́ LAUTECH márùn-ún pẹ̀lú awakọ̀ ló jóná nínu ìjàmbá mọ́tò
Ìjọba Oyo kò ní gbára lé owó láti òkè mọ́, á dojú kọ owó lára ìrìnàjò afẹ́ - Olatunbosun
Sọ́jà méjìlá kú ní Niger torí ìkọlù àwọn alákatakítí ẹ̀sìn
Ète ìdìtẹ̀gbàjọba wáyé ní Burkina Faso, ọwọ́ tẹ àwọn ológun tó fẹ́ dìtẹ̀gbàjọba
Àwàdà la fi mọ̀ mí àmọ́ àwọn èèyàn ń pè mí fún àdúrà gbígbà ju àwàdà lọ - Wolii Arole
Ọ̀pọ̀ ajínigbé ya bo abúlé Alálùbọ́ṣà ní Kwara, ẹ̀mí bọ́, ọ̀pọ̀ farapa
Kí ni Autopsy? Báwo la ti ń ṣe é, ọjọ́ mélòó ni èsì rẹ̀ máa ń jáde?
Iléeṣẹ́ ọmọ ogún òfurufú Nàìjíríà rọ òjò àdó olóró lé ibùba IPOB ní Imo, Anambra
Awọn ibuba ọmọ ikọ IPOB to wa ni ipinlẹ Imo ati Anmabra la ti rọjo ado oloro le lori.
Ikede ree ti ileeṣẹ ọmọ ogun ofurufu Naijiria fi sita lẹyin ti wọn lawọn doju ija kọ ikọ agbesunmọmi IPOB to n ja fun idasilẹ ilẹ Biafra ati awọn igun agbebọn rẹ taa mọ si ESN.
Agbẹnusọ ileeṣẹ ọmọ ogun ofurufu Gabriel Gabkwet lo fidi ọrọ yi mulẹ ninu atẹjade kan to fi sita lỌjọru.
Gẹgẹ bo ṣe wi, awọn doju ija kọ awọn ibudo ikọ yi lọjọ Iṣẹgun laaye ọtọọt lawọn ipinlẹ mejeeji yi.
Awọn ibi to ni ikọlu naa ti waye ni He identified the locations as Mother Valley Orsumughu in the Nnewi South Local Government Area (LGA) of Anambra State and Aku Ihube in the Okigwe LGA of Imo State.
O ni ṣaaju lawọn ọmọ ogun ti kẹfin pe awọn ikọ agbesunmọmi yi n gbero lati da ilu ru kaakiri awọn ipinlẹ to wa ni ila oorun guusu Naijiria.
Bo tilẹ jẹ wi pe ileeṣẹ ọmọ ogun ofurufu ko darukọ pato iye awọn to farakasa ninu iṣẹlẹ yi, agbẹnusọ wọn sọ pe ''awọn gbagbọ pe ikọlu yi so eso ree nitori awọn ri ina to ṣẹyọ lẹyin ti wọn ju ado oloro yi ati pe pupọ awọn agbesunmọmi yi lo sa asala fẹmi wọn nibi ti wọn ti n kora jọ''
Wo ibùdó ìgbafẹ́ pàtàkí nílẹ̀ Yorùbá to le pa owo gọbọi wọle fáwọn ìpínlẹ̀ tí wọn wà
Nǹkán mẹ́rin pàtàkí nípa ọjọ́ ìbí Anọbi fáwọn Mùsùlùmí
Wo ẹ̀sùn mẹ́rìnlá tí ilé aṣòfin Ondo fẹ́ fi yọ igbákejì gómìnà, Aiyedatiwa nípò
"Ohun tó wù mí jùlọ ni kí n ṣí ara àti orí sílẹ̀ àmọ́ wọ́n kan Hijab nípá fún mi láti wọ̀"
Ìdí rèé tí àwọn ènìyaǹ kan kò fi gbàgbọ́ nínú kòkòrò àìfojúrí
Wo Aisha Shoneye, akẹkọọ ọmọ ọdun mẹtadinlogun to dari ikọ elere idaraya to gba N100m ẹbun ẹkọ ọfẹ