Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Njẹ o mọ idi abajọ t'igbimọ alalaaji NaHCON fi sun gbedeke owo sisan fun irinajo Hajj ọdun 2025 siwaju?
O ya bun mi gbọ ọ
Alaga ajọ naa sọ pe ọpọ eeyan to fẹ lọ si Mecca lọdun yii ni ko lanfaani lati forukọ silẹ titi ti gbedeke ọjọ kọkanlelọgbọn oṣu kinni fi kọja
Igba wo wa ni gbedeke tuntun bayii
Alaye wa lori BBC.Com/Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Nítorí ọ̀rọ̀ Orò, ìjọba ti mọ́ṣáláṣí Jimọ kan pa
Gbọ na, ki lo kawọn Oloro pẹlu mọṣalaaṣi?
Bẹẹ laa bi ni o, adari iṣẹ ijọba ni ilu Savè lo paṣẹ pe ki wọn ti mọṣalaaṣi ọhun pa
Ki ni idi abajọ igbesẹ yii gan an ati pe nibo niluu ọhun wa?
Ti o ba fẹ mọ, Kan soju opo BBC.Com/Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ apinaka IBEDC ti gunlẹ iyanṣẹlodi niluu Ilorin
Agbẹnusọ fawọn oṣiṣẹ IBEDC sọ fun BBC Yoruba wi pe
Eti ikun lawọn alaṣẹ ileeṣẹ naa n kọ sawọn nnkan tawọn beere fun lẹnu iṣẹ'
Fun ẹkunrẹrẹ.....




























