Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Igbo ni wọn n gbin dipo Koko kaakiri oko nipinlẹ Edo bayii
Ta lo sọ bẹẹ?
Ajọ NDLEA to n gbogun ti lilo egboogi oloro ni Naijiria ni
NDLEA sọ pe ọpọ eeka ilẹ to jẹ igbo ọba ni awọn oniṣẹ ibi fi n gbin igbo si bayii
Bẹẹ ni wọn tun n ta a kaakiri Naijiria
Igbesẹ wo ni ajọ naa wa gbe bayii
Sare lọ soju opo BBC.COM/Yoruba bi o ba fẹẹ mọ
*****************************************************************************
Ileeṣẹ ologun Naijiria lawọn ti rọwọ to afurasi marun-un
Awọn afurasi wo niyẹn?
Awọn afurasi ti wọn lọ ṣe ikọlu si ibudo ologun ti Operation Burst to wa niluu Igbeti, ipinlẹ Oyo
Ileeṣẹ ologun sọ pe aṣọ ologun ti wọn ji ko
Ni awọn afurasi naa n wọ ki ọwọ too tẹ wọn
***************************************************************************
Ọọpẹ o, orileede Kenya ni orile-ede Afrika akọkọ
Ti yoo gba idije agbaye World Athletics Championship fun ọdun 2029 lalejo
Aṣeyọri yii lo waye lẹyin ti Kenya fidi London, Munich ati Rome rẹmi
Ninu igbiyanju lati gba tikẹẹti orileede ti yoo gba awọn lalejo


