BBC News, Yorùbá - Ìròyìn
Ìròyìn tó ṣe kókó
Ìgbà èwé Toluwanisings le, ọkadà bàbá rẹ̀ ló fi ń gbérò láti rí owó jẹun, ó tún ṣe lébìrà kó tó lu àlùyọ - Ọ̀rẹ́ tímọ́ olóògbé
Nibi eto abẹla titan tawọn eeyan naa se fun oloogbe yii, ni wọn ti kọ oniruuru orin onigbagbọ, ti wọn si wọ asọ dudu lati se ọfọ akọrin ẹmi naa.
"Mo rí ìjọba amúnisìn, mo rí ìgbòmìnira, mo rí ogun àti àlááfíà. Nínú gbogbo rẹ̀, ìbẹ̀rù Ọlọ́run ni mo dì mú" - Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa Reuben Fasoranti olórí ẹgbẹ́ Afẹnifẹre tó jáde láyé
Nigba aye rẹ, Baba Fasoranti sọ pe irinajo oun pẹlu Afẹnifẹre ti jẹ ki oun mọ laisiyemeji pe ifaraẹnijin nikan lohun ti wọn n pe ni ipo adari.
Wo bí o ṣe lè dá ẹni tó ní Ebola mọ̀, àti bí o ṣe lè dènà rẹ̀
Minisita feto ilera nilẹ Naijiria, Ọjọgbọn Muhammed Ali Pate lo fidi iroyin naa mulẹ fawọn akọroyin lọjọ Iṣẹgun, ogunjọ, oṣu Kẹwaa, ọdun 2026.
Fídíò, Florence Oyeyemi, obìnrin, ẹni ọdún 38 tó ń díje sílé aṣojúṣòfin, Duration 2,30
Ẹni ọdun mejidinlogoji ni Oyeyemi to n dije sipo aṣojuṣofin lati lọ ṣoju ẹkun idibo Ekiti/Irepodun/Isin/Oke-Ero lati ipinlẹ Kwara to si ba BBC News Yoruba sọrọ lori irinajo rẹ ninu oṣelu.
Wo ohun tó yẹ kí o mọ̀ nipa àyẹ̀wò fóònù kí o tó rà á
Koodi ti NCC pe ni *315# ni awọn ọmọ Naijiria yoo tẹ sori foonu tuntun ti wọn ṣẹṣẹ fẹẹ ra lati le fidi rẹ mulẹ boya ojulowo ni foonu naa tabi ayederu.
"Ibọn ba mi ni igba aya lọjọ naa, titi di oni, mi o ri idajọ ododo gba", Ọdun mẹ́fà lẹ́yìn ìwọ́de EndSARS ṣé ìdájọ́ òdodo tí wáyé?
Iwọde naa jẹ ọkan gboogi lara awọn iwọde to milẹ titi julọ ni Naijiria ati kaakiri ilẹ adulawọ lasiko naa.
"Dọ̀tun, ṣé mi ò ní kú ṣá?" Ìbéèrè tí Dele Giwa bi dókítà tí wọ́n gbé lọ sílé ìwòsàn rẹ̀ kó tó jáde láyé
Dokita naa ni pẹlu ọgbẹ ti oun ri lara rẹ, oun mọ pe o san ki Dele Giwa ku ju ko ye lọ.
DSS gbé àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nńú jíjí àwọn àgùnbánirọ̀ tó lọ láti Ibadan sí Imo lọ sílé ẹjọ́
Awọn afurasi naa nkoju ẹsun mẹta lati ori ijinigbe kan ninu awọn ohun ija oloro lọwọ.
Orin, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́, Duration 1,00
Àkójọpọ̀ ìròyìn káàkiri àgbáyé tí kò ṣe è má gbọ̀ ọ́
Ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ lọ́wọ́, ẹ̀wọ̀n lẹ́sẹ̀, ọwọ́ òfin tẹ pásítọ̀ àti ìyàwó rẹ̀ tó ń so àwọn èèyàn mọ́lẹ̀ ní ìjọ wọn
Ọgba naa to wa labẹ akoso ile ijọsin agbegbe Mpumalanga, la gbọ pe awọn agbofinro ṣawari rẹ l'Ọjọbọ, ọsẹ to kọja yii.
Seyi Makinde àti ìjọba àpapọ̀ tako ara wọn lórí ₦250b owó NLNG
Makinde ni o yẹ ki ijọba apapọ pin owo naa amọ niṣe lo jẹ gaba le lori amọ ijọba apapọ ni ko ri bẹẹ.
Ojú rí kí n tó rí ètò tó mú èèyàn 51,000 wo sinimá tí mo fi gba àmì ẹ̀yẹ GWR ṣe – Omowunmi Dada
Ọmọwunmi Dada ni awọn fẹ fihan awọn eeyan pe kii ṣe ile iworan sinima nikan leyan le gbe sinima lọ fun wiwo.
BBC News Yorùbá ti wà lórí ìkànnì WhatsApp
Má jẹ́ kí etí rẹ ó di sí gbogbo ìròyìn ohun tó ń lọ ní Naijiria àti káàkiri àgbáyé. Mọ̀ nípa wọn lórí ìkànnì Whatsapp rẹ
Ìròyìn Àkàgbádùn
Pásítọ̀ tó ṣokùnfá ikú ọ̀pọ̀ èèyàn ní Kenya jẹ̀bi ẹ̀sùn 191 tí wọ́n fi kàn án
Paul Mackenzie atawọn ọmọ ijọ rẹ mọkandinlọgbọn mii ni wọn fẹsun ipaniyan awọn ọmọde 191 kan.
Iléeṣẹ́ PoS kan tún ṣíwọ́ iṣẹ́ ní Nàìjíríà, ìdí rèé
Gẹgẹ bi ohun ti a gbọ, iye awọn to n lo POS Baxi le ni 90,000 kaakiri Naijiria.
Fídíò, Sharafadeen Alli, olùdíje APC l'Oyo ṣàlàyé ohun àti Olubadan lórí ọ̀rọ̀ ìdìbò ọdún 2027
Oludije naa ṣalaye pe bo tilẹ jẹ pe ọmọ Ibadan ni awọn yoku tawọn jọ n dupo yii, o da oun loju pe oun ni gbogbo Ibadan ati ipinlẹ Oyo lapapọ yoo dibo yan.
Ohun tó yẹ kí o mọ̀ nípa Emmanuel Uduaghan, gómìnà tẹ́lẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Delta tó jade láyé lẹni ọdún 71
Ninu atẹjade ti ọkan lara awọn mọlẹbi gomina tẹlẹ naa, Toju Anire Uduaghan fi sita lorukọ mọlẹbi, o sọ pe ibanujẹ ọkan lo jẹ fun awọn.
Dele Giwa: Èyí ni àlàyé bí wọ́n ṣe fi àdó olóró pa àgbà akọ̀ròyìn yìí lásìkò ìjọba olọgun
Ọdun 1986 ni Dele Giwa jade laye lẹyin to tẹwọ gba ado oloro ti wọn fi sinu lẹta ni ọfisi rẹ nipinlẹ Eko.
Ìṣẹ́ àti òṣì ló mú mi lu ọmọ ní Gbànjo ₦2m, afurasí ṣàlàyé fún ọlọ́pàá
Ẹgbẹrun lọna ẹẹdẹgbẹta Naira (₦500,000) ni arabinrin naa ni oun ṣi gba ninu owo naa ki wọn to deee lọna ati ri ọmọ naa.
Ta ni Tenia Abraham, òṣèré tíátà tó jáde láyé lẹ́ni ọdún 32?
Tenia Abraham, ẹni ọdun mejilelọgbọn ni awọn ẹbi rẹ kede iku rẹ loju opo Instagram rẹ lọjọ meji sẹyin pe o dagbere faye ni ọjọ Kẹtala, osu Kẹwaa, ọdun 2026.
Adunni Ade, gbajúmọ̀ òṣèrè tíátà pàdánù màmá rẹ̀
"Inna lillahi wa inna ilayhi raji'un. Loootọ, ọdọ Allah la ti wa, ibẹ naa la o si pada si," Adunni Ade kọ ọ bẹẹ soju opo rẹ.
Ìgboro ti dàrú ní France lẹ́yìn ìfẹ̀hónúhàn tó wáyé níbẹ̀, ọlọ́pàá mú èèyàn 1,200
O kere tan, eeyan 1,200 ni agbofinro ti fi ṣikun ofin mu lẹyin ti ifẹhonuhan naa gbọna mii yọ, ti eeyan bii 550,000 si ya si aarin igboro.
Ìyá ta ọmọ oṣù kan ní mílíọ́nù méjì náírà n'Ibadan
Yatọ si iya naa, ọwọ tun ba afurasi ti wọn lo ta ọmọ naa fun, to jẹ ẹni to ni ile igbẹbi to bimọ si.
Ọ̀gá àgbà àjọ FRSC Ogun; Oludare Ogunjobi, dágbére fáyé lẹ́yìn oṣù mẹ́fà tó dépò
Oni ọjọ Aiku, ọjọ kejidinlogun oṣu Kẹwaa ọdun 2026 ni Alukoro FRSC Ogun, Afolabi Odunsi, fi atẹjade to kede iku naa sita.
Láti ọdún 1996 ni mo ti ní àrùn itọ ṣúgà, bí mo ṣe ń tọ́jú ara mi rèé – Jide Kosoko
Agba oṣere naa sọ pe laipẹ yii ni wọn tun sọ foun pe wọn fẹ wo gbogbo nnkan to wa ninu oun lati mọ boya arun jẹjẹrẹ ti wa ni ibikan.
Ìròyìn Pàtàkì
Kọ́milẹ́kọ̀ọ́
Ẹ tẹ̀lé wa lórí ìkànnì ayélujára
Ìwádìí kíkún lóríi kókó ìròyìn
Mo ṣetán láti tẹ́tí sí gbogbo ohun táwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Ekiti bá n fẹ́
Gomina naa lo sọ eyi nibi eto iburawọle fun saa keji iṣejọba rẹ, eyi to waye niluu Ado-Ekiti tii ṣe olu-ilu ipinlẹ Ekiti.
Ibugbamu ipinle Edo ati Rivers mu ki ọpọ eeyan padanu okoowo wọn ti ọpọ si di alainile lori mọ.
Awọn ibugbamu yii mu ki ọpọ eeyan padanu okoowo wọn ti ọpọ si di alainile lori mọ.
Fídíò, Mi ò lè dìbò fún Peter Obi lọ́dún 2027, bẹ́ẹ̀ni kò sí aáwọ̀ láàrin wa - Gbadebo Rhodes-Vivour, Duration 2,57
Mi ò lè dìbò fún Peter Obi lọ́dún 2027, bẹ́ẹ̀ni kò sí aáwọ̀ láàrin wa - Gbadebo Rhodes-Vivour
Ṣé lóòótọ́ ni ẹbí Toluwanisings ń bẹ̀bẹ̀ ìrànwọ́ owó fún ìyàwó àtàwọn ọmọ rẹ̀ lẹ́yìn ikú olóògbé? Ohun tí a mọ̀ rèé
Iwe ilewọ kan to ti lu ori ayelujara pa bayii lo wa loju opo Instagram kan ti wọn n pe ni The Tolaoluwa Foundation eyi ti wọn fi n bẹbẹ iranwọ owo fun iyawo atawọn ọmọ oloogbe.
Kàyééfì: Nítorí ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, àwọn jàǹdùkú ṣekú pa Bàbá, Ìyá àti ọmọ mẹ́rin n'Ibadan
Ṣugbọn ni bayii, ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Oyo ti sọ pe ọwọ awọn ti tẹ afurasi mẹta to lọwọ ninu iku awọn idile naa, ati pe awọn ti bẹrẹ iwadii lori wọn.
Kò pẹ́ tí Toluwanisings kọrin tán níbi ìpàtẹ orin ẹ̀mí ló ṣubú lulẹ̀ – Amúgbálẹ̀gbẹ́
Ninu ifọrọwalẹwo kan to ṣe pẹlu gbajumọ oṣere, Biola Adebayo, Talk to B, sọ pe inu ẹsin Islam ni wọn bi oun si ati pe orin Fuji gan—an ni oun fi bẹrẹ.
Gomina Seyi Makinde la n fi ẹsun kan pe o da ibẹru oselu silẹ tori o ti pasẹ fawọn awakọ ero pe ki wọn maa lo ami idamọ ẹgbẹ oselu APM nikan soso lẹnu isẹ wọn - APC Oyo
Owurọ ọjọru ana ni isẹlẹ naa waye ni adugbo Molete nibi ti awọn ọmọ ẹgbẹ oselu Accord to lọwọọwọ si lati fi tijo tilu pade Oriyomi Hamzat to tilẹ UK de.
Kò sí ààyè fún ọkùnrin láti wọ yẹtí tàbí di irun wá sí Mọṣalaṣi wa mọ́- Shiekh Ayanbadejo Muftaudeen
Ikede naa sọ pe ofin yii yoo bẹrẹ si ni fẹsẹ mulẹ lati ọjọ Eti, ojọ kẹrindinlogun, oṣu kẹwaa, ọdun 2026 yii.
Pásítọ̀ figbeta: ''Ìta ti sú mi, mo fẹ́ẹ́ padà sílé mi tí mo ti sá kúrò láti oṣù karùn-ún nítorí ìbẹ̀rù bandiiti''
Oruganjọ ni awọn ọlọpaa wa kilọ fun pasitọ naa ati idile rẹ lati file wọn silẹ, nitori awọn agbebọn fẹẹ ṣọṣẹ lagbegbe naa niluu Idofian, ipinlẹ Kwara
'Adeleke kọ́ ló máa sọ ẹni táwọn èèyàn ìpínlẹ̀ Osun máa dìbò fún, kìí olórí ẹgbẹ́ Accord'
Egbe oṣelu All Progressive Congress (APC) ti kede orukọ awọn ti yoo wa ninu ipolongo eto idibo to m bọ ti yoo ri si bi Aarẹ Bola Tinubu yoo ṣe wọle saa keji gẹgẹ bii aarẹ Naijiria lẹẹkan sii.
Ìdí rèé tí a fi yọ orúkọ Ladi Adebutu olùdíje ẹgbẹ́ PDP kúrò nínú orúkọ àwọn olùdíje sípò Gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun - INEC ṣàlàyé
Ṣaaju ni ẹgbẹ oṣelu PDP ẹka ti ipinlẹ Ogun fẹsun kan ẹgbẹ oṣelu alatako APC wi pe oun lo ko ajọ INEC ni papamọra lati yọ orukọ Adebutu kuro ninu orukọ awọn oludije sipo gomina fun eto idibo ọdun 2027 to n bọ.














































































