You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Ta ni yóò jẹ Ọba dá ìjà sílẹ̀, òjò làásìgbò ń sú ni Iralepo Isinkan nílùú Akure
Sunday Igboho fún Abubakar Malami àti ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà lési ẹ̀sùn ìgbésùnmọ̀mí tí wọ́n fi kàn án
Ṣé lóòtọ́ ni Sunday Igboho ń gbowó ìgbésùnmọ̀mí lọ́wọ́ agbódegbà Boko Haram kan gẹ́gẹ́ bí Malami ṣe sọ?
Iléesẹ́ ọlọ́pàá Ghana mú akọrin tàkasúfèé, Shatta Wale nítorí ayédèrú ìròyìn pé ẹnì kan yinbọn mọ́ ọn
Àlàyé rèé lórí ohun tó ń fa ẹ̀kúnwó gegele lórí owó orí afẹ́fẹ́ ìdáná gáàsì
Bimbo Oshin ṣàlàyé ọ̀rọ̀ ìkẹyìn tí ọkọ rẹ̀ sọ fun un kó tó kú
Godwin ṣá bàbá rẹ̀ ládá pa nítorí orí adìyẹ, Ó ní...
"Olórí ọmọ ogun Islamic State ní Ìwọ̀ Oòrùn Afrika, ISWAP ti jáde láyé"
"A ti fòfin de ìdẹ́yẹsí nítorí ẹ̀yà ara ìbálòpọ̀ lójú òpó Facebook"
Ẹ wo bí arákùnrin kan ṣe fi ọrún àti ọfà pa èèyàn márún ún
"Akitiyan wa ti ń so èso rere, àdínkù ti ń bá bí àwọn agbésùmọ̀mí ṣe ń kọlu àwọn ọmọ Naijiria"
Akokoro eyín lè ṣe ìpalára fún àtọ̀ ọmọkùnrin, ó sì lè ṣàkóbá fún ọkàn èèyàn - Dókítà
"Á fimú Odunlade Adekola dánrin tó bá kọ̀ láti ṣe àtúnṣe lórí títàbùkù ẹ̀sìn Islam nínú fíìmù rẹ̀"
Buhari, wá nǹkan ṣe sí àwọn agbésùmọ̀mí àti agbébọn tó ń pẹ̀ka bí ìrókò-Afenifere
Iyorchia Ayu di alága tuntun fún ẹgbẹ́ òṣèlú PDP
Kò sí iṣẹ́ fún òṣìṣẹ́ ọba tí kò bá gba abẹ́rẹ́ àjẹsára títí December 1 - Ìjọba àpapọ̀
Ìgbésẹ̀ tà ń gbé rèé lórí ìlera Sunday Igboho àti ìtúsílẹ̀ rẹ̀ - Ilana Ọmọ Oodua
"Ẹ tètè gbé Sunday Igboho lọ fún ìtọ̀jú lókè òkun, kó tó pẹ́ jù"
Buhari, dáríjin Igboho àti Kanu láti fòpin sí ìjìjàgbara ní Naijiria - Bíṣọ́ọ́bù ìjọ Elétò