You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Mílíọ́nù méje èèyàn ni ìdọ̀tì inú afẹ́fẹ́ "Air polution" ń pa lọ́dọodún - WHO

  2. Gbogbo òṣìṣẹ́ ọba l‘Osun, abẹ́rẹ́ Covid-19 di ọ̀rànyàn fún yín bíbẹ́ẹ̀ kọ́... Oyetola

  3. Ẹ̀yin oníṣègùn ìbílẹ̀, ẹ bá wa ṣe àwárí oògùn àjákálẹ̀ àrùn covid-19- Ìjọba Naijiria

  4. Femi Ojudu faṣọ iyí mọ́ Kayode Fayemi lára, Ó ní ojú ń gba òun ti fún ipò táwọn títì Ekiti wà

  5. Sunday Igboho ránṣẹ́ tuntun nípa agbẹjọ́rò rẹ̀ ní Benin republic, Ó ní...

  6. Wo iye àwọn tó ti gbẹ̀mí ara wọn ní Nàìjíríà láàrin ọdún mẹ́rin ìjọba Buhari

  7. Bí ọwọ́ wa kò bá tẹ àwọn tó lọ́wọ́ nínú ìkọlù sí ọgbà ẹ̀wọ̀n Kabba, a kò ní sinmi- Aregbesola

  8. Ọ̀gá ọlọ́pàá Èkó kàn sí ẹbí Monsurat tí ọlọ́pàá yìnbon lù

  9. Báyìí ni ìrìnàjò àìsàn Iyabo Oko ṣe bẹ̀rẹ̀ láti ọdún márùn ún ṣẹ́yìn

  10. Ọlọ́pàá Eko ní àwọn ti mú aríbọnyọ̀ ọlọ́pàá tó yìnbọn pa arábìnrin kan ní Ijeshatedo

  11. Ṣọ́ọ̀ṣì wó pa èèyàn méjì ní Taraba, àwọn míràn farapa

  12. Wo iye kọ́ńdọ́mù táwọn ọmọ Nàìjíríà fi ń ṣara rindin lọ́dún

  13. Ọmọ Naijiria tó ń ṣe Yahoo rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ̀rin he l'Amẹrika

  14. "Kò sí ìdáríjí fún àwọn jàndùkú mọ́ báyìí, a óò bẹ̀rẹ̀ sí ń ran wọn lọ sí ọ̀dọ̀ Eledumare"

  15. Ọ̀kan lára àwọn ọmọ Odunlade Adekola nídìí iṣẹ́ tíàtà sọ̀rọ̀ sókè lórí ẹ̀sùn pé ó ń bá àwọn lòpọ̀

  16. Ọ̀bẹ ti bá ọ̀gá DPO tó sọ ìbọn ọlọ́pàá nu lẹ́yìn tó gbé obìnrin sùn sí ọ́fíìsì rẹ̀ nídí

  17. Àlàyé ohun tọ́rọ̀ adarí ń dá sílẹ̀ ní ìjọ Synagogue lẹ́yìn ikú TB Joshua rèé

  18. Ìjọba Ondo bẹ́gilé ẹgbẹ́ ọlọ́jà, ó ní wọ́n ń ni aráàlú lára

  19. Ẹ mú àrídájú jáde pé Igboho ló ni ilé tí DSS kọlù tàbí pé ẹ̀jẹ̀ èèyàn ló wà nílẹ̀ níbẹ̀ lẹ́yìn ìkọlù náà- Malami

  20. Wo akọrin Highlife kan tó ń kọrin bíi Lagbaja