You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ẹ̀jọ́ àtí ìwádìí ikú Timothy Adegoke ti kúró lọ́dọ̀ọ wa nípinlẹ̀ Osun- Agbẹnusọ Ọlọ́pàá Oṣun

  2. Ìjọba ti iléẹ̀kọ́ Ojodu pa, Ó ní àlàyé ohun tó ṣókùnkùn nípa ìjàmbà tírélà tó pa akẹ̀kọ̀ọ́ níbẹ̀ ńbọ̀ láipẹ̀

  3. Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tí wọ́n fẹ̀sùn ikú Demilade, ọmọ ọdún méje tí wọ́n bá òkú rẹ̀ nínú 'cooler' lẹ́yìn tó dàwátì ní Ado-Ekiti

  4. Ẹnikẹ́ni kò ní lè yọjú síbi ayẹyẹ kankan l'Eko láì fi ẹ̀rí hàn pé ó ti gbabẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19- Sanwo-Olu

  5. Wo ohun tó fa ariwo FRSC àti Ọlọ́pàá gangan nínú ìṣẹ̀lẹ̀ tó gba ẹ̀mí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní Ojodu Berger

  6. Omicron: Kíni ìdí tí Nàìjíríà ṣe wà lára àwọn orílẹ̀-èdè tó léwu láti rírínàjò lágbàyé?

  7. Èèyàn mẹ́ta míì tún ti lùgbàdì ẹ̀dà COVID-19 tuntun Omicron ní Nàìjíríà

  8. Wolii Sotitobire jáde lọ́gbà ẹ̀wọ̀n!

  9. Ramon Adedoyin t'ọ́lọ́pàá mú nítorí ikú Timothy Adegoke gba ilé ẹjọ́ lọ, ohun tílé ẹjọ́ sọ rèé...

  10. Ìgbésẹ̀ láti dínà arìnrìnàjò ọmọ Nàìjíríà sí UK yóò da ètò rú fáwọn tó fẹ́ bá ẹbí wọn ṣe Kérésìmesì ní UK

  11. Mẹ́ta lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Dowen College tí Sylvester dárúkọ ti wà ní àkàtà ọlọ́pàá - Kọmisanna ọlọpaa Eko

  12. Àwọn ilé ẹjọ́ ní Naijiria yòó bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe ìgbẹ́jọ́ lórí ayélujára

  13. Fásitì fi ọwọ́ òsì júwe ilé fún olùkọ́ tó nawọ́ eré ìfẹ́ sí akẹ́kọ̀ọ́

  14. Wó ìgbésẹ̀ táwọn ọlọ́pàá gbé níwájú iléẹ̀kọ́ Dowen College tí Sylvester Oromoni tó kú lọ

  15. 'Ọmọ mi mẹ́rin, ọmọ àbúrò mi mẹ́ta ló wà lára àwọn ọmọ tí wọ́n bá òkú wọ́n nínú ọkọ̀'

  16. Ẹ̀ wo bàbá àgbàlagbà tó lo ayédèrú apá nitorí kò fẹ́ gba abẹrẹ́ àjẹsára Covid-19

  17. Ọgọ́ta èèyàn tí àwọn jàndùkú jí gbé nínú ìjọ Baptist ní Kaduna ti gba ìtúsílẹ̀

  18. Wo ohun tí àwọn ọmọ Naijiria sọ lórí ikú akẹ́kọ̀ọ́ Dowen College, Sylvester Onoromi

  19. Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn òbí ọmọ ọdún 15 tó yìnbọn pa èèyàn mẹ́rin nílé ẹ̀kọ́

  20. Wo orílẹ̀èdè tí ẹ̀dà Covid-19 tuntun Omicron rápálá wọ̀ l‘Áfíríkà