You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.
Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Buhari kíyèsára, gbèsè Naijiria pọ̀ ju owó tó ń pa wọlé lọ - AfDB
Àṣìṣe márùn ún tí àwọn lọ́kọláyà ńṣe nípa owó
Agbébọn yabo Catholic Seminary ní Kaduna, wọ́n jí èèyàn mẹ́ta, ọ̀pọ̀ farapa
Ìdí rèé tí ń kò fi máa lo bàálù àdáni - Oluwo
Buhari, ohun ìjà tó ń kójọ ni wọn yóò lò láti rẹ́yìn Nàíjíríà - Fr Mbaka
Gómìnà Yoruba, ẹ dúró lé ìjọba àpapọ̀ lọ́rùn pé kó fi Sunday Igboho sílẹ̀ - Gani Adams
Buhari, fa iwé òfin ọdún 1999 ya, ko sì pe ìpàdé àpérò aráàlú - Yorùbá VOR
Okùnrin yìí ra àpò ìrẹsì mẹjì, ó fi ọmọ méjì sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi owó
Ṣé o mọ̀ pé o leè kó Covid pẹ̀lú ọmọ ìka ẹ̀sẹ̀ rẹ̀ láì mọ̀?
Ẹ wo àwọn adarí ìjọ ní Naijiria tó tako abẹ́rẹ́ àjẹ́sára Covid-19 àti àwọn tó faramọ
Nǹkan ṣẹlẹ̀ l'Abuja, Ondo àti Eko lọ́jọ́ Òmìnira
Irọ pátápátá ní pé a lọ́wọ́ nínú ikú Dókítà Chike Akunyili - Àjọ DSS
Ọlọ́pàá, Amotekun àti figilanté kán lu igbó láti wá àwọn tó pa ọlọ́pàá méjì ní báńkì Iragbiji, Osun
A óò fi imú gbogbo àwọn tó ṣekúpa ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Eko dárin - Sanwo-Olu
Sotitobire pe ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn lórí ẹ̀wọ̀n gbére
Wo ohun tí ọlọ́pàá sọ nípa 'Charlie', ajá tó gé kórópọ̀n akẹ́kọ̀ọ́ fásitì AAUA jẹ l'Ondo
Ayẹyẹ ọdún Ọlọ́jọ́ fẹjú bí iná alẹ́ ní Ilẹ Ifẹ̀
Wo kókó ọ̀rọ̀ márùn ún tí Buhari sọ níbi ìpàdé àjọ UN l'Amẹrika
Ọ̀gá ọlọ́pàá pàdánù ẹ̀mí rẹ̀ lásìkò tí wọ́n lọ fi ṣìkún òfin mú àwọn ọlọ́kadà nílùú Eko