You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. 'Omicron ti wọ Nàìjíríà o', ìjọba àpapọ̀ kéde; Canada bẹ́gi dínà àwọn ọmọ Nàìjíríà tó bá fẹ́ wọlé

  2. 'Láti Dec 1, iṣẹ́ ọjọ́ mẹ́rin péré láàrín ọ̀ṣẹ̀ ní àwọn òṣìṣẹ́ yóò máa ṣe báyìí'

  3. Wo ìdí tí àwọn Ọba aládé mẹ́rin yìí ṣe darí ìfẹ̀hónúhàn l'Ekiti

  4. Wo àwòrán àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó péjú síbi ìsìnkú Baba Suwe

  5. Àwọn ọlọ́pàá ti ń wá okùnrin tó gbé òkú ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ sínú fííjì lẹ́yìn tó gbẹ̀mí rẹ̀ tán

  6. Ọdún tó ń bọ̀ ni okọ̀ òfúrufú ‘Air Nigeria’ yóò gbérasọ

  7. Malawi kọ lẹ́tà sí Mike Tyson pé kó di asojú wọn fún ewé ọlà, igbó

  8. Femi Fani-Kayode ṣàlàyé bí ìrìnàjò rẹ̀ sọ́dọ̀ EFCC ṣe jẹ́

  9. Kò sí ìfẹ̀míṣòfò kankan ní Lekki Too Gate, àlọ́ àpamọ̀ lásán ni èsì ìgbìmọ̀ EndSARS - Lai Mohammed

  10. Rúdurùdu nílé aṣòfin l‘Ogun, Igbákejì olórí ilé ní wọ́n lo ayédèrú ìbuwọ́lù òun láti gbé ₦50m jáde

  11. Àìsàn ‘Dementia’ ló ń bá ọkọ́ mi Olu Jacobs fínra láti ọdún díẹ̀ - Joke Silva

  12. Kanpe ni òkú Timothy Adegoke wà, wọn kò gé ẹ̀yà ara rẹ̀ - Ọlọ́pàá Osun

  13. Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko rún alùpùpù 482 tí wọ́n gbà lọ́wọ́ àwọn ọlọ́kadà jégé-jégé

  14. Mo ti ṣetán láti pín ₦250m sí ilé àwọn ọmọ aláìníyàá káàkiri Naijiria - Davido

  15. Àṣẹ̀yìnwá àṣẹ̀yìnbọ̀, Ijọba Eko sọrọ lórí àbọ̀ ìgbìmọ̀ igbẹjọ́ lórí #EndSARS

  16. 'Ó ṣeéṣe kí ẹ̀dà ìwé àbájáde ìwádìí ìgbìmọ̀ EndSARS tó lu sórí ayúlujára yàtọ̀ sí èyí t'íjọba yóò gbé jáde'

  17. Kí ló fa rúgúdù láárín ọlọ́pàá àtàwọn ọlọ́kadà ní Obalende, l'Eko?

  18. Ilé ẹjọ́ gba béèlì àwọn òṣìṣẹ́ ilé ọmọ aláìlóbìí méjì tí wọ́n lo ta ọmọ obìnrin alárùn ọpọlọ

  19. Ajàfẹ́tọ́ obìnrin tó wá sí Nàìjíríà torí àwọn akẹ́kọ̀ọ́bìnrin Chibok tí wọ́n jígbé Malala Yousafzai ṣe ìgbéyàwó

  20. Ìjọba àpapọ̀ kéde ètò “Operation Feed Yourself” láti pèsè ọ̀pọ̀ oúnjẹ yanturu