You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ olórí pátápátá fún àwọn ajínigbé kan l'Ekiti

  2. Tóo bá ń múra láti jápaa, wò ìlànà tuntun tí Amerika gbé kalẹ̀ fáwọn tó bá fẹ́ wọ ilẹ̀ wọn báyìí

  3. Wo ọ̀rọ̀ tí gómìnà ìpínlẹ́ Ogun sọ lẹ́yìn tó ṣàbẹ̀wò sí bàbá Femi Osibona tó kọ́ ilé tó dà wó l'Eko

  4. Erin wó! Orí Adé kan ti wàjà l'Oyo

  5. Àwọn ojíṣẹ́ Ọlọ́run tó yí Buhari ká kò bá a sọ òtítọ́ ọ̀rọ̀- Afenifere

  6. Èèyàn 94 kú lásìkò tí wọ́n ń gbọ́n epo bẹntiróòlù

  7. Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ nílé ẹjọ́ lónìí lórí ìgbẹ́jọ́ Baba Ijesha

  8. Gómìnà díbọ́n bíi aláìsàn lọ ṣèwádí aṣemáṣe àwọn òṣìṣẹ́ iléèwòsàn, ọ̀rọ̀ kọ sísọ

  9. Kí ló wà láàrin Olorì Badra àti Bobrisky, tí ọ̀rọ̀ wọn fi wọ̀?

  10. Wàhálà ń bẹ ní Nàíjíríà bí wọn bá tún tako ọmọ onílùú láti wọlé - Soyinka

  11. Wo orúkọ tuntun tí Facebook yóò má jẹ́ láti àkókò yíì lọ

  12. Ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ àtàwọn èèyàn Sango-Ota ti òpópónà Eko sí Abeokuta pa nítorí ọ̀nà tí kò dára

  13. Darandaran kan rí ẹ̀wọ̀n gbéré he ní Ekiti

  14. Bí ìgbẹ́jọ́ Naira Marley ṣe lọ lọ́jọ́ Iṣẹ́gun rèé

  15. Ìbúgbàmù míì ti wáyé lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Abolongo l'Oyo

  16. Boko Haram fi tipa fẹ́ mi fún ọkọ àmọ́ ìfẹ́ rẹ̀ gbóná lọ́kàn mi ni ń kò fi sá kúrò

  17. Ìfẹ́ ńlá rèé o! Ọmọbabìnrin pàdánù ipò ọlá rẹ̀ láti fẹ́ atàpátadìde ní ọkọ

  18. Olórí àwọn ọlọ́dẹ Oyo tú iṣu dé ìsàlẹ̀ ìkòkò bí àádọta agbébọn ṣe kọlu ọgbà ẹ̀wọ̀n Abolongo

  19. “Ẹkùn Àríwá rí sáà ìṣèjọba Buhari bíi àdánù ní wọn ṣe tako pínpín ipò ààrẹ”

  20. Amotekun àti Sọ́jà kú lásìkò tí wọn já ọgbà ẹ̀wọ̀n Abolongo l‘Oyo - Makinde