Wo orílẹ́èdè 62 táwọn èèyàn ibẹ̀ kò nílò fisà láti wọ orílẹ́èdè Germany

Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 3

Orilẹede Germany ti kede orilẹede mejilelọgọta kan tawọn eeyan ibẹ ko nilo fisa lati wọ orilẹede naa.

Gẹgẹ bii atẹjade ti ẹka ijọba orilẹede Germany to n ri si ọrọ ilẹ okeere fi sori itakun agbọrọkaye wọn, awọn eeyan lati orilẹede mejilelọgọta yii lanfaani lati ṣabẹwo si Germany fun aadọrun un ọjọ fun irinajo igbafẹ, ipade okoowo ati igbadun ẹbi.

Ṣugbọn irufẹ awọn eeyan yii ko le lanfaani lati ṣiṣẹ ti wọn yoo maa gbowo lasiko abẹwo wọn si Germany.

Awọn to ba fẹ ṣiṣẹ tabi ti wọn ba fẹ maa gbe ni Germany nilo lati gba fisa ti yoo fun wọn lanfaani lati ṣe bẹẹ.

Awọn eeyan kan naa si tun wa ti wọn koju oṣuwọn lati gba fisa lati maa gbe ni Germany, amọ, eyi ni ṣe pẹlu bi ofin orilẹede ti wọn ti wa ba ṣe ri.

Wọnyi lawọn orilẹede tawọn eeyan ibẹ ko nilo fisa lati wọ orilẹede Germany fun igba kan:

Albania

Andorra

Antigua and Barbuda

Argentina

Australia

Bahamas

Barbados

Bosnia and Herzegovina

Brazil

Brunei

Canada

Chile

Colombia

Costa Rica

Dominica

El Salvador

Georgia

Grenada

Guatemala

Honduras

Hong Kong (SAR passport holders)

Israel

Japan

Kiribati

Kosovo

Macao (SAR passport holders)

Malaysia

Marshall Islands

Mauritius

Mexico

Micronesia

Moldova

Monaco

Montenegro

New Zealand

North Macedonia

Nicaragua

Palau

Panama

Paraguay

Peru

Saint Kitts and Nevis

Saint Lucia

Saint Vincent and the Grenadines

Samoa

San Marino

Serbia

Seychelles

Singapore

Solomon Islands

South Korea

Taiwan

Timor-Leste

Tonga

Trinidad and Tobago

Tuvalu

Ukraine

United Arab Emirates

United Kingdom

United States

Uruguay

Vanuatu

Vatican City

Venezuela

Ẹwẹ, awọn orilẹede mejilelọgọrun un yii lawọn eeyan ibẹ nilo lati gba fisa wọ orilẹede Germany.

Afghanistan, Algeria, Angola, Armenia, Azerbaijan, Bahrain, Bangladesh, Belarus, Belize, Benin, Bhutan, Bolivia, Botswana, Burkina Faso, Burundi, Cambodia, Cameroon, Cape Verde, Central African Republic, Chad ati Nigeria.

Awọn orilẹede mii ni China, Comoros, DR Congo, the Republic of the Congo, Côte d'Ivoire, Cuba, Djibouti, the Dominican Republic, Ecuador, Egypt, Equatorial Guinea, Eritrea, Eswatini, Ethiopia, Fiji, Gabon, Gambia, Ghana, Guinea, Guinea-Bissau, Guyana, Haiti, India, Indonesia, Iran, Iraq, Jamaica, Jordan, Kazakhstan, Kenya, North Korea, Kuwait, Kyrgyzstan, Laos, Lebanon, Lesotho, Liberia, ati Libya.

Awọn mii ni Madagascar, Malawi, Maldives, Mali, Mauritania, Mongolia, Morocco, Mozambique, Myanmar, Namibia, Nauru, Nepal, Niger, Oman, Pakistan, the Palestinian territories, Papua New Guinea, the Philippines, Qatar, Russia, Rwanda, São Tomé and Principe, Saudi Arabia, Senegal, Sierra Leone, Somalia, South Africa, South Sudan, Sri Lanka, Sudan, Suriname, Syria, Tajikistan, Tanzania, Thailand, Togo, Tunisia, Turkey, Turkmenistan, Uganda, Uzbekistan, Vanuatu, Vietnam, Yemen, Zambia and Zimbabwe.