BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Aṣa
Nítorí ọ̀rọ̀ Orò, ìjọba ti mọ́ṣáláṣí kan pa lórílẹ̀èdè Benin
6 Èrèlè 2025
4:34
Fídíò,
Ní ìlú Igbeti òkúta iyebíye Marble ya mùrá síbẹ̀, àmọ́ kò so èso sí àpò aráàlú
, Duration 4,34
6 Èrèlè 2025
Ilé aṣòfin Oyo ní kí àwọn tó tàbùkù Soun Ogbomoso lórí rédíò Lagelu FM wá sọ tẹnu wọn
6 Èrèlè 2025
3:24
Fídíò,
Wo ìtàn tó bí oríkì 'ìjàkadì lorò Offa', àti bí wọ́n ṣe ń jà á
, Duration 3,24
3 Èrèlè 2025
Kí ló ń fa ìfànfà láàárín Gómìnà Adeleke àti Ọba ìlú Iragbiji lórí oyè Aragbiji?
2 Èrèlè 2025
Ilé ẹjọ́ yí àṣẹ Gómìnà Adeleke padà lórí ìyànsípò Owa ti Igbajo
1 Èrèlè 2025
Ìdí rèé tí Makinde fi ní káwọn òṣìṣẹ́ Oyo máa wọ Aṣọ Òkè ní gbogbo Ọjọ́bọ
30 Sẹ́rẹ́ 2025
Èèyàn méjìlá kú lásìkò táwọn èèyàn ń tẹ ara wọn pa níbi ọdún ìwẹ̀ odò
29 Sẹ́rẹ́ 2025
Àwa ọmọ Yoruba kò gbọdọ̀ jẹ́ kí àṣà wa parun, ayé ti ń fi ọwọ́ rọ́ wa sẹ́yìn – Obasanjo
27 Sẹ́rẹ́ 2025
Ìlànà Yorùbá la gbà pẹ̀tù sí Afe Babalola nínú lórí aáwọ̀ tó wà láàrin rẹ̀ àti Dele Farotimi - Ooni Ife
27 Sẹ́rẹ́ 2025
Alábàṣiṣẹ́ Mukaila Ṣẹnwẹlẹ ṣàlàyé ohun tó ṣe kẹ́yìn kó tó jáde láyé
25 Sẹ́rẹ́ 2025
Ǹjẹ́ Alaafin Oyo tuntun lè rìnrìn àjò lọ sókè òkun láì tíì wọ Ìpẹ̀bí? Àlàyé rèé
24 Sẹ́rẹ́ 2025
Ohun tó mú ẹlẹ́wọ̀n tí Gómìnà Adeleke dá sílẹ̀ dèrò ẹ̀wọ̀n padà lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́jọ tó gbòmìnira
22 Sẹ́rẹ́ 2025
Ọba Ghandi Soun Ogbomoso, ẹ má bínú gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ tí mo bá ṣẹ̀ yín - Ìmáàmù Àgbà bẹ̀bẹ̀
21 Sẹ́rẹ́ 2025
Wọ́n ti kéde ọjọ́ ayẹyẹ ìgbadé Alaafin Oyo tuntun
20 Sẹ́rẹ́ 2025
Nǹkan tó yẹ kóo mọ̀ nípa ọdún Oshoosi ní Ile Ife
19 Sẹ́rẹ́ 2025
Àwọn Oyomesi wà níbi tí mo ti dífá tó mú Aláàfin Oyo tuntun - Ọ̀jọ̀gbọ́n Wande Abimbola
18 Sẹ́rẹ́ 2025
3:37
Fídíò,
''Fifi ẹnu yẹpẹrẹ Ìṣẹ̀ṣe ni ìlú fi ń dàrú, a ti fi ọ̀nà àwọn baba ńlá wa sílẹ̀''
, Duration 3,37
18 Sẹ́rẹ́ 2025
1:00
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 1,00
15 Sẹ́rẹ́ 2025
3:11
Fídíò,
Láyé àtijọ́, Èṣù ni wọ́n máà ń pe ìlu Àgídìgbo, kò sí ibi tí wọn ti lù ú, tí ìjà kìí bẹ́ sílẹ̀ - Onílù Àgídìgbo
, Duration 3,11
15 Sẹ́rẹ́ 2025
Wo Alàáfin 45 tó jẹ́ láti ìgbà ìwásẹ̀, ṣáajú Abimbola Owoade
15 Sẹ́rẹ́ 2025
"Makinde ti tàpá sí òfin àti àṣà ìlú Oyo lórí ìyànsípò Aláàfin, yóò kábàmọ̀ ohun tó ṣe lọ́jọ́ iwájú"
15 Sẹ́rẹ́ 2025
Aláàfin tuntun wọ ìlú Oyo, ariwo sọ
14 Sẹ́rẹ́ 2025
1:01
Orin,
Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
, Duration 1,01
14 Sẹ́rẹ́ 2025
Ìṣájú
Page
14
nínú
40
1
11
12
13
14
15
16
17
40
Tókàn