Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Itẹ Alaafi ko wa fun tita, maa ba gbogbo Oyomesi to ba gba riba lori iyansipo Alaafin ṣe ẹjọ
Gomina ipinlẹ Oyo, Seyi Makinde lo sọ bẹẹ lẹyin to gbe ọpa aṣẹ fun alaafin tuntun, Ọba Abimbola Akeem Owoade
Makinde ni oun ko ni darinjin awọn to gba riba naa lailai, ayafi ti wọn ba lọ tuba fun Alaafin tuntun, to si fori jin wọn
Ọwọ ọlọpaa ipinlẹ Nasarawa ti tẹ akọrin ẹmi kan, Timileyin Ajayi
Lori ẹsun pe o pa ọrẹbinrin rẹ, Salome Enejo, to si ge ori ati ẹya ara rẹ wẹlẹwẹlẹ
A gbọ pe agunbanirọ ni oloogbe naa n ṣe niluu Abuja ki olorin ẹmi ọhun to jẹ ọrẹkunrin rẹ to gbẹmi rẹ, lati ṣetutu
Lọ soju opo BBC Yoruba fun ẹkunrẹrẹ
Ọpọ ọmọ Yoruba lo ti bu ẹnu atẹ lu Timi Àgbàlé ilu Ede, Ọba Munirudeen Adesola Lawal
Latari bo ṣe kunlẹ lati ki Emir ilu Ilorin, Alhaji Ibrahim Sulu-Gambari
Amọ ori ade ọhun ti ṣalaye ohun to ri lọbẹ to fi waru ọwọ
Fun kulẹkulẹ iroyin yiii