Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Aàbò tó péye yóò wà fún àwọn tí yóò kópa nínú ìfẹsẹwọ̀nsẹ̀ Naijiria àti Sierra Leone ní Benin - Obaseki
Sanwo Olu àti Okowa dẹwọ́ ìséde ní Eko àti Delta pẹ̀lú àlàyé tuntun
Wo ojú àwọn òṣèré yìí láì lo "Make-up" orí ìtàgé bó ṣe rí gẹ́lẹ́
Orúkọ àwọn tó yege láti darapọ̀ mọ́ ikọ̀ Amotekun ní ìpínlẹ̀ Oyo ti jáde
'Àwọn òṣèré aparí pọ̀ táa ti ṣe iṣẹ́ abẹ irun fún tẹ́ẹ ma rò pé wọ́n gẹ "low cut" ni'
Ọlọ́pàááá! Ẹ padà sẹ́nu iṣẹ́ kíá bí bẹ́ẹ̀ kọ́... Àmọ́ ẹ ríi pé ẹ dáàbò bo ẹ̀mí yín - Ọ̀gá àgbà ọlọ́pàá
Mo pinu láti dá Iphone tì mo mú padà kí ọlọ́pàá tó mú mi
Eyitayo Jegede gbé Akeredolu lọ síwájú ìgbìmọ̀ tó n gbọ́ ẹ̀sùn ìdìbò
Àwọn olóṣèlú Nàìjíríà márùn ùn tó sọ̀rọ̀ tí ará ìlú fà ìbínú yọ
Ẹ gbọ́ Ohun tí Desmond Elliot àti Mojisola Alli-Macaulay sọ lórí ayélujára táwọn ọmọ Nàìjíríà fi ìbínú
Ìjọba Eko kọ orúkọ sí "Palliatives" tiwọn lára o, mo ní ẹrù tèmi f'ọjọ́ ìbí mi tí wọ́n jí - Họ́nọ́rébù Agunbiade
Àwàdà tàbí óótọ́, kì lò f'ẹkún Kọmíṣọ́nnà ìlera Kogi lórí amóhùnmáwòrán?
Tóo bá pá lórí, Mílíìkì sóyà àtàwọn ǹkan mẹ́ta yìí leè mú irun rẹ hù padà!
Kìí ṣe ebi, ìyà tàbí ìṣẹ́ ló mú kí wọ́n yabo àwọn ilé ìkẹ́rùsí - Femi Adeshina
Ìjọba ìpińlẹ̀ Eko ti kédé ìwọlé àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ní gbogbo iléèwé aládàni àti ìjọba
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun ti pàṣẹ kí wọ́n ṣí gbogbo ilé ìjọsìn, ilé ìgbafẹ́ padà lẹ́kúnrẹ́rẹ́, Covid 19: Ìjọba ìpínlẹ̀ Ogun pàṣẹ kí wọ́n ṣí gbogbo ilé ìjọsìn, ilé ìgbafẹ́ padà lẹ́kúnrẹ́rẹ́

Oríṣun àwòrán, Prince Dapo Abiodun MFR
Gomina ipinlẹ Ogun, Dapo Abiodun ti paṣẹ ki awọn ile ijọsin, mọsalasi, ile iwobọọlu, papa iṣere, ile ounjẹ ṣi pada lẹkunrẹrẹ ni ipinlẹ Ogun.
Dao Abiodun lo fi igbesẹ tuntun naa lede ninu atẹjade ti akọwe eto iroyin nipinlẹ naa, Kunle Solomon fi lede.
Awọn ileeṣẹ wọnyii di titi pa lati dawọ itankalẹ ajakalẹ arun Covid-19 duro nipinlẹ naa’
Gomina Abiodun ni oun fẹ ki ohun gbogbo pada sipo lọtun nipinlẹ naa.
‘’Ile itura, ile itaja, ile ounjẹ, sinima, ati gbogbo awọn ile igbafẹ ti le ṣi pada lẹkunrẹrẹ bayii’’
‘’Awọn ile ijọsin kaakiri naa le bẹrẹ isin wọn pada lai si idaduro tabi iye eniyan to le e wa si ile ijọsin lẹẹkan naa’’
‘’ Amọ, awọn ileeṣẹ ati ile ijọsin yii gbọdọ tẹle ofin ijinasiraẹni ati fifọwọ loore-koore lati le dẹkun itankalẹ arun Coronavirus yii.’’
Gomina ipinlẹ Ogun, Dapo Abiodun naa fikun wi pe awọn ti pese ile ayẹwo ati awọn ileewosan silẹ nipinlẹ naa lati tete ṣe ayẹwo arun Coronavirus fun awọn eniyan ni iye ti ko ni na wọn lowo ju.
Gomina Abiodun ni igbese naa pọn dandan nitori ati mu ki idagbasoke ba ọrọ aje ipinlẹ naa, eleyii ti o ni arun Coronavirus ti ṣe akoba fun.
Nitori naa o rọ awọn eniyan lati ma a ṣe ayẹwo ara wọn ti wọn ba de ile igbafẹ, ki wọn si tẹle ofin ijinasiraẹni naa.
Ẹ̀kọ́ ọ̀fẹ́ déé fáwọn ọmọ Ọlọ́pàá tó kú lásìkò EndSARS, Gómìnà Sanwo-Olu kéde
Báyìí ni 50 Kobo ṣe dá ìfẹ̀hónú "Ali Must go" sílẹ̀ tó mú ọ̀pọ̀ ẹ̀mí akẹ́kọ̀ọ́ lọ
Ọlọ́pàá mẹ́fà, àgọ́ ọlọ́pàá márùn-ún ló bá wàhálà ìwọ́de #ENDSARS lọ nípìnlẹ̀ Oyo - Kọ́mísánnà
