Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Àwọn ọmọ Nàìjíríà yarí lórí èròngbà ilé aṣòfin pé kí àjọ FRSC má a lo nkan ìjagun

  2. Wo ìdí márùn-ún tí Biden fi bórí nínú ìdìbò ààrẹ America

  3. Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ mánigbàgbé tó wáyé nínú oṣù Kẹ́wàá ọdún 2020

  4. Wo ìgbà márùn ún tí Buhari ti rìnrin àjò lọ sókè òkun fún ìtọ́jú ara rẹ̀

  5. Ẹ wo ẹyẹ ayékòótọ́ tó kó olówó rẹ̀ yọ lọ́wọ́ ikú gbígbóná

  6. A ti gbé ìwádìí dìde lórí ìpànìyàn tó wáyé lásìkò ìwọ́de EndSARS- Ilé ẹjọ́ àgbáyé, ICC

  7. Oṣú mẹ́fà ni òṣìṣẹ́ ìjọba tó bá bímọ yóò máa lò nílé kó tó wọṣẹ́ padà- Seyi Makinde

  8. ₦50 bílíọ́nù ni a pín fún gbogbo ìpínlẹ̀ ní Naijiria láti kojú àrùn Covid-19- Ìjọba àpapọ̀

  9. Ọkùnrin kan rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́rin he lẹ́yìn tó jí ẹ̀rọ ìléwọ́ iPhone ní ìpínlẹ̀ Ogun

  10. Ẹ fún wa lówó oṣù wa tàbí kí a gùnlé ìyanṣẹ́lódì ọlọ́jọ́ gbọọrọ- Àwọn dokita ìpínlẹ̀ Ondo

  11. Ṣé ẹ̀yin ti rí ọkùnrin tó ń sún ẹ̀kún ìyàwó rí?

  12. Ìjọba ti buwọ́lu lílo hijab láwọn iléèwé ní ìpínlẹ̀ Osun

  13. Mọ̀ síi nípa òwò jìbìtì tuntun Crowd 1 tó gbòde kan lásìkò yìí

  14. Inú mi máa ń bàjẹ́ ni tí mo bá ti rí SARS- Fasasi Tiamiyu

  15. Kíní ọ̀nà àbáyọ sí ìjàmbá ọkọ̀ tó ń wáyé lemọ́lemọ́ ní Ọjà Akungba,ní Ondo?

  16. EFCC bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí ẹ̀sùn ìwà jẹgúdújẹrá tí wọ́n fi kan Fowler tó jẹ́ Alága iléeṣẹ́ FIRS tẹ́lẹ̀

  17. ''Àjọ NERC ti fún Disco láṣẹ láti padà sí owó tàríìfù tuntun iná mọ̀nàmọ́ná''

  18. Ẹ dẹ̀kun lílo Sniper àti Dichlorvos fún ìtọ́jú oúnjẹ- NAFDAC kìlọ̀

  19. Oluwo ti ìlú Iwó kìí ṣe ẹgbẹ́ Àtaọjà Osogbo - Alaafin ìlú Ọ̀yọ́

  20. Wo iye owó tí ìjọba Amẹrika ń na sí ìdìbò Ààrẹ àti ibi tí owó náà ti ń wá