Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Kà nípa ohun tí Alaafin Oyo sọ nípa "ìkòkò ọbẹ̀" àwọn ọmọ Nàìjíríà lọ́jọ́ Kérésìmesì
Àwọn àmi méje tó ń tọ́ka sí pé oò kí ń mu omi bí ó ti tó
Odunlade Adekọla, Lateef Adedimeji, , Mercy Aigbe àtàwọn òṣèré míì tó fi àsìkò Kérésì ya àwọn olólùfẹ́ wọn lẹ́nu
Kí ló mú àwọn ẹni ọdún 90 méjì yìí ṣẹ̀ṣẹ̀ máa gbéyàwó lásìkò yìí?
Àwọn Tíṣà Oyo kó owó tó wà fún àkóso iléèwé jẹ, ni wọ́n fi ń fọwọ́ kọ ìdánwò pẹ̀lú ṣọ́ọ̀kì - Seyi Makinde
Ohun márùn ún tóo gbudọ̀ mọ̀ nípa ìtàn àti ayẹyẹ ọdún Kérésì
Ẹ̀yin ṣọ́ọ̀ṣì àti Mọ́ṣáláṣí, mo wọ́gilé ìsìn àṣálẹ́ àìsùn ọdún àti ìṣọ́ òòru - Sanwo-Olu
'Pasuma, Fathia Balogun, Femi Davies, gbogbo wọ́n di èèyàn mi tórí DJ orin Fújì nìkan tí mò yàn láàyò'
Kàyééfì rèé! Aláìsàn fìbínú lù aláìsàn ẹgbẹ́ rẹ̀ pa nítorí pé ó ń gbàdúrà lẹ́gbẹ́ rẹ̀
Wo bí àjọyọ̀ ọdún ṣì ṣe lè wáyé ní ìpínlẹ̀ rẹ̀ lọ́dún yìí nítorí COVID-19
Ohun tí a mọ̀ nìyí nípa #IGotSurvivalFund owó ìrànwọ̀
'Irọ́ ni aráàlú pa, Amotekun kò yìnbọn pa èèyàn méjì ní Ibadan, a lọ bá wọn mú jàǹdùkú ni'
Wo ohun tí Pasuma sọ nípa Opeyemi, ọmọ rẹ tó di ọmọ ogun orí omi l'Amẹrika
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ ayédèrú Ahmed Musa tó ń lu àwọn èèyàn ní jìbìtì
'Ọ̀lọ́pàá shátà mi láti Mowe dé Magboro dé Shagamu, wọ́n ní ṣé mi ò mọ̀ pé ìjọ́ba ni mo ṣiṣẹ́ fún'
Bí o bá rí Erin tí alùpùpù gbá lójú pópó, kí lo ó ṣe?
Buhari sí ìgbìmọ̀ PTF: Ẹ̀ máà bá iṣẹ́ yín lọ títí dì 2021
Joe Biden náà ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsara Covid-19
Dùndú rẹ ń láta! Ó yẹ kí àwọn ọlọ́pàá mú Lere Olayinka fún ìwà ọ̀daràn - Oyo PDP
