Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Ìdí tí mi ò fi lè parí ìjà pẹ̀lú Ààrẹ Ọ̀nà kakanfò, Gani Adams - Obasanjo
Ọwọ́ wa ti tẹ àwọn afurasí tó lọ́wọ́ nínú ikú Olufon ti Ifon, Oba Israel Adeusi - Amotekun
Abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 ti Pfizer ṣe yóò di lílò láti ọ̀sẹ̀ tó ń bọ̀
Àwọn afurasí ṣá ìgbákejì kọmísọ́nà ọ̀gá ọlọ́pàá láàké dójú ikú
'Àwọn ọmọ 5 kọ́ ló sọnù, ọmọ 28 ló sálọ síléeṣẹ́ foyúngbowó nípinlẹ̀ Ogun'
Soun ilẹ̀ Ogbomoṣo pàdánù ọmọkùnrin rẹ̀
Ọlọ́pàá 200 ni yóò máa ṣọ́ ibojì Diego Maradona torí àwọn olè
Ṣé lóòtọ́ ni ìjà ti parí láàrin ìdílé Ayinde Barrister àti Kwam 1?
Iná sọ ní abáwọlé Eko, ọkọ̀ agbépo tún tí gbiná lórí afárá Magboro
Wọ́n ti rẹ ipò ọ̀gágun Olusegun Adeniyi sílẹ̀ lẹ́yìn tó jẹ̀bi títú àṣírí kùdiẹ-kudiẹ iléeṣẹ́ ológun lórí ayélujára
'Dẹ́rẹ́bà wa ọkọ̀ kọjá lórí "Poly Bag" lásán, kò mọ̀ pé àdó oloró ni! Ọkọ mi ló forí la ikú'
Wo ohun tí wọ́n sọ nípa Owa Ale ìlú Ikare, Ọba Samule Kolapo Adegbite Adedoyin tó wàjà
Awakọ̀ agbókùú, ọlọ́pàá, ológun, oníròyìn ló máa ń kọ́kọ́ dìbò ní Ghana, bó ṣe ń lọ rèé
'Ẹ sọ́ra fún "Christmas Carol", ẹ̀yin tẹ́ẹ sì wà lókè òkun ẹ má wálé o!'
Gbọ́ ìtàn Ọba ilẹ̀ Yorùbá tó pàṣẹ kí òjò rọ̀ ní orílẹ̀èdè Cuba lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ oṣù
Kàyééfì! Kòkòrò oyin sọ ọ̀pọ̀ èèyàn di aláìrílégbé, àwọn míràn tún farapa
Mi ò ṣe ẹ̀tánú Ọọ̀ni ilé Ifẹ̀, ọmọ ìyá mi ni ṣùgbọ́n...-Olugbo Obateru Akinruntan
Ẹ wo ìdí tí Oby Ezekwesili ṣe ń pè fún àyẹ̀wò ọpọlọ fún Ààrẹ Buhari
Wo ohun tó ṣẹlẹ̀ sí àwọn ọba tó kọ ifá sílẹ̀ gbé Bíbélì àti Kùránì
