Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Àfàìmọ̀ ká máa dá ìforúkọsílẹ NIN dúró tórí ewu coronavirus- Mamora
Ìlú tuntun tó kún fún ohun àdáyébá láìsí ọkọ̀ tàbí òpópónà ń bọ̀ ní Saudi Arabia
Àpapọ̀ àwọn tó ti ní Coronavirus ní Naijiria ti lé ní 100,000 báyìí
Wo àwọn Ọ̀jọ̀gbọ́n fásitì tí àrùn Coronavirus gbẹ̀mí wọn
Àwọn olorì Aláàfin fi oríkì awúnilórí yẹ́ ọkọ wọn sí fún àádọ́ta ọdún tó gorí ìtẹ́
Buhari, pa ìtìjú mọ́ra láti sanwó fáwọn ajaguntà tí yóò kojú Boko Haram - Soyinka
Nígbà wo ni ìsìnkú Orisabunmi yóò wáyé?
O dí gbére! Iléeṣẹ́ Twitter tí ojú òpó Ààrẹ Donald Trump lórí ẹ̀rọ rẹ̀ pa
Ẹ gbà mí o, wọ́n ti ń fi kóló mi kó àwọn èèyàn lómi ọbẹ̀ jẹ- Tawa Ajisefinni
"Ọjọ́ méjì péré ni Orisabunmi lò níléèwòsàn kó tó jáde láyé"
Ìjọba àpapọ̀ jáwọ́ lórí àfinkún owó iná fún ìgbà díẹ̀
"Ikọ́ lásán ló pa Orisabunmi"
Èèyàn 32,720 kó ààrun COVID-19 l'Eko nìkàn, Sanwo-Olu bá figbe ta
Ẹ gbọ́ ohun tí Ifá, ẹlẹ́rí ìpín sọ rí nípa ìlú Ibadan àti ìwà ìmẹ́lẹ́
''Ewu ń bẹ pẹ̀lú coronavirus táwọn akẹ́kọ̀ọ́ ba wọlé padà báyìí l'Eko''
Ètò Akọ́mọlédè Yorùbá gbé "Gbólóhùn Yorùbá" yẹ̀wò lọ́sẹ̀ yìí
Ọlọ́pàá Oyo n wa afurasí tó ṣekú pa oníṣòwò àti ọmọ ọdún mẹ́sán án méjì ní Ibarapa
Nǹkan márùn ún tó yẹ kí o mọ̀ nípa Ọ̀gá Àgbà fásitì UNILAG tẹ́lẹ̀rí, Ibidapo Obe tó jáde láyé
Dúró! Kí o tó sọ ìwọ́ àti olubi ọmọ rẹ nù, wo 80 àwọn àrùn tí o lè fi wò nínú ìdílé rẹ
