Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́

Àkọlé fọ́nrán ohùn, Kò ṣe é má gbọ̀ ọ́
Published
Ìye àkókó tí a fi kà á: Ìṣẹ́jú 1

Àwọn góminà tó fàáké kọ́rí lórí ìlànà tuntun nípa àtúnṣe owó orí ti pahùndà pé àwọn faramọ ìlànà tuntun naa

Ṣaaju ni awọn gomina iha ariwa ti kọkọ sọ pe owo ori tuntun ọhun yoo ṣakoba fun awọn

Awọn gomina ti wa ṣatupalẹ bi wọn yoo ṣe maa pin owo ti ijọba ba pa wọle lori VAT

Alaye wa loju opo BBC Yoruba

Aarẹ Amẹrika, Joe Biden ti fun ọmọ Naijiria mẹfa ni ami ẹyẹ

Lati mọ riri ipa ribiribi ti wọn n ko nipa imọ sayẹnsi lagbaye

Awọn eeyan naa ni Tomi Akindele, Azeez Butali, Ijeoma Opara, Oluwasanmi Koyejo, Abidemi Ajiboye ati Eno Ebong

Nipinlẹ Ondo

Ẹgbẹ oṣelu PDP ti sọ pe awọn ko ni kopa ninu eto idibo ijọba ibilẹ ti yoo waye lọla ọjọ Abamẹta

Ẹgbẹ oṣelu naa sọ fun BBC pe eredi igbesẹ ọhun ko ṣẹyin igbagbọ awọn pe

Ajọ eleto idibo ipinlẹ Ondo, ODIEC, yoo ṣegbe lẹyin APC ninu ibo ọhun

Amọ APC ti ni ahesọ ọrọ lasan ni

Ti o ba fẹ mọ bo ṣe n lọ