BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo aarẹ Naijiria 2023
Bola Tinubu tó di ààrẹ, PDP àbí APC ni yóò gbè fún nínú ìbò gómìnà l‘Oyo?
3 Ẹrẹ̀nà 2023
''Èsì ìdíbò kíkà ọdún 2023 yóò tẹ̀síwájú, kìí ṣe tí 1999 tí ẹ dàrú '' - APC
28 Èrèlè 2023
Wo olùdíje ààrẹ tó wà lókè ténté nínú èsì ìbò ìpínlẹ̀ mẹ́rìnlà tí INEC kéde
28 Èrèlè 2023
Ọ̀rọ̀ àlùfàǹsá ni Obasanjo sọ, ó fẹ́ dojú ìjọba alágbádá bolẹ̀ ni - Tinubu
28 Èrèlè 2023
"Mo gbọ́ ìró ìbọn ní àgọ́ ìdìbò, mo sì ri tí ẹ̀jẹ̀ ń dà lójú mi"
27 Èrèlè 2023
Ẹ̀yin ará Eko, ẹ gba àlááfíà laaye, mìmì kan kò le mìwá – Asiwaju Ahmed Tinubu
27 Èrèlè 2023
Èsì ìbò dá ìjà sílẹ̀, èèyàn mẹ́rin kú, wọ́n gún 42 ní ọ̀bẹ
27 Èrèlè 2023
Wo ọ̀pọ̀ ìgbésẹ̀ tàwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà gbé láti dáààbò bo ìbò wọn
27 Èrèlè 2023
Ìbò ààrẹ́ dá ìjà rọ̀fọ̀rọ́fọ̀ sílẹ̀ lágbo tíátà Yorùbá
27 Èrèlè 2023
PDP tó jáwé olúborí l'Osun látòkè délẹ̀ fihàn pé àwọn ará Osún nígbàgbọ́ nínú mi gẹ́gẹ́ bíi Gómìnà wọn - Adeleke
27 Èrèlè 2023
BBC finmú-fínlẹ̀ lórí ìròyìn tó ní IINEC ń lo ojú òpó ayélujára rẹ̀ láti yí èsì ìdìbò
26 Èrèlè 2023
Wo àwòrán mánigbàgbe ìdìbò ààrẹ àti tàwọn aṣòfin àpapọ̀
26 Èrèlè 2023
Ó dùn mí pé ń kò le dìbò, ẹ̀rọ BVAS kò rí ojú àti ìka mi - Osoba
25 Èrèlè 2023
Ẹ̀ lọ sùn lálẹ́ òní, ó di ọ̀sán ọ̀la ká tó bẹ̀rẹ̀ ìkéde èsì ìdìbò - INEC
25 Èrèlè 2023
Tọkọtaya gbọgbẹ́ ní àgọ́ ìdìbò bí agbébọn ṣe jí àpótí ìbò mẹ́ta lọ
25 Èrèlè 2023
Jàndùkú kọlù òṣìṣẹ́ EFCC tó ń tọ̀pinpin ìbò ní Abuja àti Imo
25 Èrèlè 2023
Ọ̀pọ̀ èèyàn farapa lásìkò tí àwọn jàndùkú kọlu àwọn alátìlẹyìn Kwakwanso ní Kano
24 Èrèlè 2023
Ọwọ́ Ọlọ́pàá tẹ ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin pẹ̀lú $498,100 ní Rivers
24 Èrèlè 2023
Ìjọba àpapọ̀ pàṣẹ kí wọ́n ti gbogbo ẹnubodè ilẹ̀ tó wọ Naijiria fún wákàtí mẹ́rìnlélógún
24 Èrèlè 2023
Lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ wákàtí, Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Finland tú adelé olórí IPOB, Simon Ekpa sílẹ̀
24 Èrèlè 2023
2:09
Fídíò,
Ebi ń pa wá, kò sówó ṣùgbọ́n síbẹ̀, a máa dìbò yan ẹni tó wù wá- Awọn ọmọ Nàìjíríà
, Duration 2,09
24 Èrèlè 2023
Ẹ gba kámú lórí ẹni tí INEC bá kéde pé ó wọlé, àlááfíà Nàìjíríà ni mo fẹ́- Buhari
24 Èrèlè 2023
Bí ìgbáradì fún ètò ìdìbò ṣe ń lọ káàkiri ilẹ̀ Yorùbá nìyí
23 Èrèlè 2023
5:20
Fídíò,
'Àwọn ọkùnrin gan mọ̀ pé àwọn nílò àwa obìnrin nínú òṣèlú, ìdí tí èmi fi wọ òṣèlú ni pé...'
, Duration 5,20
23 Èrèlè 2023
Ìṣájú
Page
10
nínú
34
1
7
8
9
10
11
12
13
34
Tókàn