BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Awọn ọmọde
12:00
Fídíò,
'Ògì ni mó rán Demilade lọ rà, ẹ̀ṣẹ̀ táa ṣẹ Pásítọ̀ Mr Olajiga kò yé mi tó fi gé òkú ọmọ wa wẹ́lẹ́wẹ́lẹ́, ẹ gbà mí ooo!'
, Duration 12,00
14 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Wo orílẹ́èdè tó fẹ́ fi òfin de sìgá mímú fún ìran ọmọ wọn tó ń bọ̀
10 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Gbogbo àwọn tó lọ́wọ́ nínú ikú Sylvester Oromoni kò ní lọ láì jìyà lábẹ́ òfin - Buhari
9 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí tí wọ́n fẹ̀sùn ikú Demilade, ọmọ ọdún méje tí wọ́n bá òkú rẹ̀ nínú 'cooler' lẹ́yìn tó dàwátì ní Ado-Ekiti
8 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Mẹ́ta lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Dowen College tí Sylvester dárúkọ ti wà ní àkàtà ọlọ́pàá - Kọmisanna ọlọpaa Eko
7 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
"Kí ló dé tó jẹ́ orúkọ ẹbí Kashamu nìkan lẹ mú bọnu nínú àwon ọmọ Marun ti Oromoni Jnr dárúkọ?"
7 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Àbùkù ńlá ni ikú Sylvester Oromoni jẹ́ fún ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó- ìyàwó Gómìnà Sanwo-Olu
6 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Báwo ni àwọn ọmọ méje ṣe di òkú sínú ọ̀kọ̀ àyọkẹ́lẹ̀ kan ní Badagry
5 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Aṣọ ń pe aṣọ rán níṣẹ́ ni lónìí nílé ìjọsìn Wolii Sotitobire lẹ́yìn tí ilé ẹjọ́ tú olùdásílẹ̀ wọn sílẹ̀
5 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Wo ohun tí àwọn ọmọ Naijiria sọ lórí ikú akẹ́kọ̀ọ́ Dowen College, Sylvester Onoromi
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn òbí ọmọ ọdún 15 tó yìnbọn pa èèyàn mẹ́rin nílé ẹ̀kọ́
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Wo ọ̀ná tí àwọn ọkùnrin lè gbà ṣe ìfètòsọ́mọbíbí láì lo kọ́ndọ́ọ̀mù lásìkò ìbálòpọ̀
28 Bélú 2021
Ọmọ tuntun tí wọ́n bá lórí pẹpẹ ṣọ́ọ́ṣì gba orúkọ tuntun
27 Bélú 2021
"Màá pa màálù fún ọ, ọmọ mi Khadija, tí mo bá rí ọ gbà padà lọ́wọ́ ajínigbé"
27 Bélú 2021
"Akẹ́kọ̀ọ́ 1,440 ní iléẹ̀kọ́ 25 ni àwọn agbébọn ti jígbè lọ ní Naijiria"
25 Bélú 2021
'Mi ò fìgbà kankan fura pé ọkọ mi lè fi ọmọ wa ṣe òògùn owó'
13 Bélú 2021
Ilé ẹjọ́ gba béèlì àwọn òṣìṣẹ́ ilé ọmọ aláìlóbìí méjì tí wọ́n lo ta ọmọ obìnrin alárùn ọpọlọ
11 Bélú 2021
Wọ́n ti bẹ̀rẹ̀ ètò ìsìnkú àwọn akẹ́kọ̀ọ́ 26 tó jóná mọ́ yàrá ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn
9 Bélú 2021
Ìkúnlẹ̀ Abiyamọ oo! Ìyá ju ọmọ rẹ̀ méjì sí Kànga
6 Bélú 2021
7:54
Fídíò,
Wo àwọn ọmọ tí àìsí èròjà protein ń dà láàmú, tí òbí wọn rò pé iṣẹ́ ayé ni
, Duration 7,54
6 Bélú 2021
Ọwọ́ tẹ oníṣègùn níbi tó ti ń sin ọmọ tuntun láàyè pẹ̀lú ọfọ̀ àti àyájọ́
4 Bélú 2021
5:13
Fídíò,
Kàyèéfì! Mo ní àrùn jẹjẹrẹ tẹ́lẹ̀ àmọ mo bí ìbejì lẹ́yìn tí nǹkan oṣù ti dúró - Olorì Olugbon
, Duration 5,13
3 Bélú 2021
Kí ló mú Lizzy Anjorin ṣe àyẹ̀wò DNA ọmọ rẹ̀?
1 Bélú 2021
Ọkọ àti ìyàwó ṣàlàyé ohun tó jẹ́ kí wọ́n ta ọmọ wọn ní N200,000 tí ṣe $500
26 Ọ̀wàrà 2021
Ìṣájú
Page
20
nínú
32
1
17
18
19
20
21
22
23
32
Tókàn