BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Awọn ọmọde
Kàyééfì! Àṣírí ìyá àti ọmọkùnrin rẹ̀, afurasi tó jí ọmọ ọlọ́mọ gbé fi ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó f'ọ́dún mẹ́ta tú l'Ekiti
23 Ẹrẹ̀nà 2022
Kí ló lè mú kí ìyá da bẹntiró sí ará ọmọ ọdún mẹ́wàá tó sì dáná sun ún?
22 Ẹrẹ̀nà 2022
Bàbá ẹni ọdún 60 bá ọmọ ọdún méjìlá tó jẹ́ adití àti odi lòpọ̀, ó dèrò àtìmọ́lé
20 Ẹrẹ̀nà 2022
3:24
Fídíò,
Ẹ̀mí ìjókíjó, Wòó, Ṣọ̀kí, Wojú, Ṣàkùṣákù, One Corner...jáde! Ẹ wá gba ìtúsílẹ̀ lọ̀dọ́ọ̀ Wòlìí Small Mummy
, Duration 3,24
20 Ẹrẹ̀nà 2022
"Sylvester Oromoni tọ̀ mí wá pé itan ń ro òun kó tó kú, mo sì ba fi ọwọ́ ra á pẹ̀lú òògùn ara ríro"
16 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọ̀rọ̀ bẹ́yìn yọ! Ìyá ọmọ́ yọjú pé ‘Dispatch Rider’ tí wọn ká ọmọ mọ́ lọ́wọ́, kìí ṣe gbọ́mọ-gbọ́mọ
14 Ẹrẹ̀nà 2022
Tẹ̀gbọ́n tàbúrò jí ọmọ ará àdúgbò gbé láti gbowó, àmọ́ wọn fún ní òògùn eku jẹ
13 Ẹrẹ̀nà 2022
"Èèdì àti ogun ayé ni awọn èèyàn n rò pé ó mú mi bí ìbejì ní ìgbà mẹ́fà"
13 Ẹrẹ̀nà 2022
Wo ibi tí ọ́rọ́ ìgbẹ́jọ́ Baba Ijesha dé dúró báyìí láti osù kẹrin, ọdún 2021
11 Ẹrẹ̀nà 2022
Odindi ọdún mẹ́ta ni ọkọ mi ti ń fipá bá ìbátan mi ọmọ òrukàn ọdún mọ́kànlá lò pọ̀
7 Ẹrẹ̀nà 2022
Sé lóòtọ́ ní ẹni ọdún 14 yìí fi májèlé sí oúnjẹ mọ̀lẹ́bí tó ń bá gbé ní Obada Oko? ohun tí a mọ̀ rèé..
5 Ẹrẹ̀nà 2022
Eré orí ìtàgé ni à ń ṣe nínú fọ́nrán CCTV tí wọ́n ti sọ pé mo fẹ́ bá ọmọdé lòpọ̀ - Baba Ijesha
4 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọmọ ọdún 15 tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó bá ọmọ ọdún mẹ́jọ lòpọ̀ fojú balé ẹjọ́ l'Eko
3 Ẹrẹ̀nà 2022
Omoyeni rí ẹ̀wọ̀n he fẹ́sùn fífi abẹ ya ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ lára
2 Ẹrẹ̀nà 2022
Olùkọ́ dèrò àgọ́ ọlọ́pàá lẹ́yìn tó na akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́sàn án lálubami
28 Èrèlè 2022
Ọmọ ọdún mẹ́tàlá gún ènìyàn pa nítorí owó ìrèké ní ìpínlẹ̀ Borno
27 Èrèlè 2022
Sotitobire: Ẹ wá wo ohun t'Ọ́lọ́run ń ṣe ní ìjọ mi lẹ́yìn tí mo bọ́ ní ẹ̀wọ̀n gbére tẹ́ẹ tì mí lọ
22 Èrèlè 2022
Fọ́tò àǹkóò oyún ọmọ ìyá mẹ́ta gbòde kan
18 Èrèlè 2022
"Ó ṣeéṣe kí wọ́n ti ṣe àyípadà àti àtúnṣe sí fọ́nrán tí wọ́n gbé jáde lórí ọ̀rọ̀ Bàbá Ijesha"
18 Èrèlè 2022
Wo ohun tí ìjọba ṣe fún akẹ́kọ̀ọ́ kílààsì SS 2 tó gbá Olùkọ́ létí ní Ibadan
17 Èrèlè 2022
1:15
Fídíò,
Abúlé tí wọn kìí ti sọ ọmọ ní orúkọ, ohùn arò ni wọ́n fi ń pè wọ́n
, Duration 1,15
15 Èrèlè 2022
Olùkọ́ lu akẹ́kọ̀ọ́ rẹ ọmọ ọdún kan àti oṣù méje pa ní ìpínlẹ̀ Delta, O bọ́ sí gbaga ọlọ́pàá
14 Èrèlè 2022
Àwọn tó ní mi ò lè bímọ lárùn ọpọlọ, ó nídìí tí mo fi ṣẹ̀ṣẹ̀ bímọ - Yomi Fabiyi
11 Èrèlè 2022
Small Mummy, aláwàdà ọmọ ọdún mẹwàá gba ẹ̀bùn ọkọ̀ olówó iyebíye
9 Èrèlè 2022
Ìṣájú
Page
18
nínú
32
1
15
16
17
18
19
20
21
32
Tókàn