BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ààrẹ Muhammadu Buhari
Àjọ́ CAN pàṣẹ ètò àdúrà ọlọ́jọ́ mẹ́tà fún Naijiria ní May 28 sí 30, ẹ wo kókó àdúrá...
13 Èbibi 2021
Àwọn ọmọ Naijiria yóò rí akitiyan ìjọba láti yanjú ètò àbò tó mẹ́hẹ láìpẹ́ - Lai Mohammed
11 Èbibi 2021
A ti fòfin de dída màálù ní gbangba káàkiri ilẹ̀ Yorùbá, Ibò àti ìhà Gúúsù Gúúsù - Àwọn gómìnà yarí
11 Èbibi 2021
Ìjọba dá òfin kónlé-ó-gbélé lórí àjàkálẹ̀ àrùn covid-19 padà
11 Èbibi 2021
Ìjọba Ààrẹ Buhari ti kùnà, kò le è sí ìfìmọ̀ṣọ́kan lábẹ́ ìṣèjọba rẹ̀ ní Naijiria- Wole Soyinka
9 Èbibi 2021
Wo ǹkan méje tó yẹ kí o mọ̀ nipa Mama Taraba tó jáde láyé lẹ́ni ọdún 61
7 Èbibi 2021
Àwọn ǹkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Hadiza Bala Usman tí Buhari ní kó lọ rọọ́kún ńlé
7 Èbibi 2021
Èèmọ̀ wọ̀lú! Àwọn jàndùkú agbébọn pa kọmíṣọ́nnà àti ọlọ́pàá, wọ́n dáná sun àgọ́ ọlọ́pàá
2 Èbibi 2021
Kò sí ẹ̀rí tó dájú tí a lè lò láti yọ Pantami kúró n'íjọba Buhari- Ilé aṣòfin l'Abuja
2 Èbibi 2021
Ìṣẹ̀lẹ̀ àwọn agbésùnmọ̀mí bíì Boko Haram ti dínkù lásìkò ìjọba Buhari- Fayemi
1 Èbibi 2021
Fr Mbaka kọ ẹ̀yìn sí Buhari nítorí kò rí nǹkan jẹ lábẹ́ rẹ̀ - Iléeṣẹ́ Ààrẹ
1 Èbibi 2021
Ọjọ́ Ajé gba ọ̀pọ̀ ẹ̀jẹ̀ ọmọ Nàíjíríà láti ọwọ́ àwọn agbébọn
27 Ìgbé 2021
Keyamo dójú ti ara rẹ̀ àti ìjọba tó ń sìn bó ṣe kéde ìtàkurọ̀sọ rẹ̀ pẹ̀lú Eedris fáyé - Amofin
26 Ìgbé 2021
4:54
Fídíò,
Buhari tí mo mọ̀ ní 1983 kọ́ ló wà nípò, mò ń ‘doubt’ rẹ̀ - Olugbon
, Duration 4,54
26 Ìgbé 2021
Èmi kọ́ ni mò n pín ìrẹsì lókè Ọya lásìkò àwẹ̀ yìí - Bola Tinubu
17 Ìgbé 2021
Ohun mẹ́rin tó ṣẹ̀lẹ̀ ní Nàíjíríà nígbà tí Buhari kò sí nílé
16 Ìgbé 2021
Buhari padà sí Nàìjíríà lẹ́yìn ìsinmi ráńpẹ́ ní London
15 Ìgbé 2021
Buhari yóò tẹ̀síwájú láti máa gba ìtọ́jú nílẹ̀ òkèèrè, ẹ kàn ń pariwo lásán ni - Amúgbálẹ́egbẹ́ Ààrẹ
7 Ìgbé 2021
Dáa padà! Àwọn alátìlẹ́yìn Buhari fàdúrà jagun lòdì sáwọn tó ń fẹ̀hẹ́nùhàn lé e kúrò ní London
6 Ìgbé 2021
Ọ̀rọ̀ ètò ìlera Nàìjíríà ń bẹ nínú ewu, Buhari ń fọwọ́ ra àwọn agbésùnmọ̀mí lórí - Bakare, Kukah
5 Ìgbé 2021
SERAP pe Ààrẹ Muhammadu Buhari lẹ́jọ́ lórí ₦3.8b owó ètò ìlera tó pòórá
4 Ìgbé 2021
Ìwà àjẹbánu àti títẹ̀ ẹ̀tọ́ ọmọnìyàn lójú pọ̀jù nínú ìjọba Buhari - US
1 Ìgbé 2021
Ọ̀gá ológun, kò yẹ kí jàndùkú gbàkóso agbègbè kankan ní Naijiria - Buhari
30 Ẹrẹ̀nà 2021
Buhari láṣẹ́ lábẹ́ òfin Naijiria lẹ́tọ̀ọ́ láti gba ìtọ́jú lókè òkun - Amòfin
30 Ẹrẹ̀nà 2021
Ìṣájú
Page
14
nínú
29
1
11
12
13
14
15
16
17
29
Tókàn