BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Iwa Ijẹkujẹ
Rúdurùdu nílé aṣòfin l‘Ogun, Igbákejì olórí ilé ní wọ́n lo ayédèrú ìbuwọ́lù òun láti gbé ₦50m jáde
21 Bélú 2021
Gómínà díbọn lọ ilé ìwòsàn, òṣìṣẹ ìlera tó gba rìbá N10,000 wọ gàù
5 Bélú 2021
Ọ̀gá báńkì rẹ́wọ̀n he torí ó fi N219m owó oníbàárà kọ́ ilé, ra ilẹ̀
3 Bélú 2021
Àwọn adarí iléẹ̀kọ́ wọ gàù fún gbígba owò lọ́wọ́ àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lọ́nà àìtọ́
3 Bélú 2021
EFCC gbé bàbá olówó Obi Cubana
2 Bélú 2021
Wo bí àwọn agbófinró ṣe ya bo ilé Onídájọ́ Mary Odili pẹ̀lú àwọn ohun tuntun tó súyọ
30 Ọ̀wàrà 2021
Ìjọba fẹ́ ẹ́ lu kọ́mú, góòlù N14bn àti ilé N32bn tó jẹ́ ti mínísítà eporọ̀bì tẹ́lẹ̀, Diezani ní gbàǹjo
27 Ọ̀wàrà 2021
Mompha pàdánù èròjà olówó ìyebíye mọ̀kànlá sọ́wọ́ EFCC
16 Ọ̀wàrà 2021
N kò lẹ́bọ lẹ́rù lórí ilé Tinubu ní London tí ìwé Pandora gbé jáde pé mo ba rà á - Oyetola
10 Ọ̀wàrà 2021
5:32
Fídíò,
Ìyàwó Aṣọbodè, Sọ́jà àti Ọlọ́pàá náà ń kó ẹrù wọlé sí Nàìjíríà lọ́nà àìtọ́- Senatọ Fadahunsi
, Duration 5,32
9 Ọ̀wàrà 2021
Ìyàwó Ganduje ti kúrò lọ́dọ̀ọ́ EFCC, wo ohun tó gbé e lọ síbẹ̀....
6 Ọ̀wàrà 2021
Pandora Papers tú àṣírí àwọn olóṣèlú jẹgúdújẹrá mẹ́wàá ní Naijiria
5 Ọ̀wàrà 2021
Àṣírí ọ̀rọ̀ àti dúkìá ìkọ̀kọ̀ ẹbí aarẹ Uhuru Kenyatta tú
4 Ọ̀wàrà 2021
Ilé ẹjọ́ ju Àfáà tó ń gbé àwọ̀ Femi Adesina wọ̀ sí ẹ̀wọ̀n ọdún 28, ó tún pàdánù dúkìá
1 Ọ̀wàrà 2021
Agbẹnusọ àjọ EFCC Wilson Uwujaren ti ṣàlàyé nǹkan tí ó ṣẹlẹ̀ sí ọ̀gá àjọ náà lósàn ọjọ́bọ
16 Owewe 2021
EFCC mú àwọn gbájúẹ̀ orí ayélujára 56 ni òtẹ́lì àti àwọn bùba mííràn ni ìpińlẹ̀ Ogun
14 Owewe 2021
Ìyà, ìṣẹ́ pọ̀! ó kéré tán 27.4M ọmọ Naijiria ní kò rí N100,000 ní ọdún - SERAP
4 Owewe 2021
Àwọn tó lu ₦6trn owó àjọ NDDC ní póńpó rugi oyin - Buhari fọnmú
3 Owewe 2021
Ẹ̀yin agbébọn, ajínigbé àti ikọ̀ afẹ̀jẹ̀wẹ̀, ìjọba mi yóò fimú yín dárin - Buhari
14 Ògún 2021
Ọwọ́ FBI yóò tẹ Abba Kyari, òǹyẹ̀ kankan kò lè yẹ̀ ẹ́ - Femi Falana
9 Ògún 2021
Ta ni èṣù láàrin ìjọ Ọlọ́run àti Hushpuppi? - Daddy Freeze bèèrè
8 Ògún 2021
Ìdí tí wọ́n fi ń pè mi ní Maradona rèé- Ibrahim Babangida
7 Ògún 2021
Jacob Zuma, ààrẹ tẹ́lẹ̀ ní South Africa rí ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́ẹ̀dógún he
29 Òkùdu 2021
Lóòótọ́ ni màmá mi ní àìsàn ọpọlọ 'Schizophrenia' kó tó kú - Iyabo Ojo
18 Òkùdu 2021
Ìṣájú
Page
10
nínú
17
1
7
8
9
10
11
12
13
17
Tókàn