BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ifiyajẹni
Agbẹjọ́rò Akwa Ibom lu ìyàwó rẹ̀ lálùbami, ọlọ́pàá bẹ̀rẹ̀ ìwádìí
19 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ afurasí ọkọ tó fá ọmọ odó yọ láti ṣekúpa ìyàwó rẹ̀
10 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
‘Àwọn ọlọ́pàá pa irọ́ ìdigunjalè mọ́ mi, gbé àwòrán mi sórí ayélujára láì ṣe ìwádìí, mo wá di ẹni tí ẹbí ọ̀rẹ́ ń sá fún’
27 Bélú 2023
‘Ọkùnrin tó fún mi ní ẹ̀bùn N200 ló pariwo pé mo ti mú nǹkan ọmọkùnrin òun’
16 Ọ̀wàrà 2023
Ìyàwó tó dá òróró gbóná sórí ọkọ rẹ̀ sàlàyé ìdí tó fí ṣe bẹ́ẹ̀ níwájú akọ̀ròyìn
14 Ọ̀wàrà 2023
Ìjọba Nàìjíríà rán èèyàn sí Igboho lọ́gbà ẹ̀wọ̀n Benin láti jáwọ́ lórí Yoruba Nation kí wọ́n lè fi sílẹ̀ – Banji Akintoye
10 Ọ̀wàrà 2023
Àwọn onímọ̀ ṣe àwárí ibùdó àkọ́kọ́ t'áwọn òyìnbó amúnisìn ń kó ẹrú pamọ́ sí ní ilẹ̀ adúláwọ̀
3 Ọ̀wàrà 2023
Obìnrin tó ba Eniola Badmus lórúkọ jẹ́ lórí Tiktok rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́ta he
3 Ògún 2023
Ọlọ́pàá ń ṣèwádìí bàbá ọmọ fún ẹ̀sùn pé ó ta ọmọ rẹ̀ mẹ́ta ní N1.5m
15 Agẹmo 2023
8:43
Fídíò,
Ìwádìí fihàn pé nínú ilé ìwòsàn 88 ní Khartoum, 61 nínú wọ́n ní wọn tí ṣèkọlù sí nínú ogun tó ń lọ lọ́wọ́ ní Sudan
, Duration 8,43
5 Agẹmo 2023
Èèyàn 160 ni agbébọn ti pa lásìkò ìjọba Tinubu, èyí burú jáì - Amnesty
14 Òkùdu 2023
Èèmọ̀ dé! Pásítọ̀ pa aláboyún àti èèyàn méjì míì, iléẹjọ́ dájọ́ yíyẹgi fún un
6 Òkùdu 2023
Àlàyé lórí bí ilé ẹjọ́ ṣe yí ìdájọ́ padà sí ọdún méjì fún òṣìṣẹ́ Rahman Adedoyin tí wọ́n dájọ́ ikú fún l’Osun
1 Òkùdu 2023
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá bẹ arákùnrin tí ọlọ́pàá la igi mọ́ lórí, gba ọ̀kadà rẹ̀ l’Eko, wọ́n ní ìjìyà tó tọ́ ti bẹ̀rẹ̀ fún wọn
19 Èbibi 2023
3:33
Fídíò,
‘Mo ti dáríjin ìbátan mi tó da ásíìdì sí mi lára’
, Duration 3,33
6 Èbibi 2023
Wo iye tí agbénipaṣètùtùọlà kan ń ta ẹsẹ̀ odindi èèyàn ní ìpínlẹ̀ Ogun
4 Èbibi 2023
Babaláwo so ọmọ rẹ̀ méjì mọ́lẹ̀, fi ebi pa wọ́n ku
20 Ìgbé 2023
Àwọn mọ̀lẹ́bí ọkùnrin tí ‘ìdun jẹ títí tó fi kú’ pè fún ìdájọ́ òdodo
15 Ìgbé 2023
6:01
Fídíò,
Àwọn tó sun ọmọ mi níná ní ó wọ aṣọ olówó ńlá táwọn kò rí irú rẹ̀ wọ̀, ni wọn ṣe pa á - Ìyá Tope Olorunfemi
, Duration 6,01
15 Ìgbé 2023
Afipábánilòpọ̀ dáná sun ara rẹ̀ lọ́gbà ẹ̀wọ̀n, ó díbọ́n pé òun kú fún ọdún kan, àṣírí tú
14 Ìgbé 2023
Ọkùnrin kan dèrò ẹ̀wọ̀n lẹ́yìn tó gùn ọ̀rẹ́ rẹ̀ lọ́bẹ pa nítorí gbèsè
12 Ìgbé 2023
Àánú ni mo ṣe fún Manny Monie, ohun tó ṣẹ́lẹ̀ láàrin wa rèé tó fi tọ ọlọ́pàá lọ - Portable
30 Ẹrẹ̀nà 2023
Ẹ san N30m owo ‘gbà má bínú’ fún Ọlọ́kadà tí Amotekun mọ̀ọ́mọ̀ yìnbọn lù - Iléejọ́
30 Ẹrẹ̀nà 2023
5:37
Fídíò,
Màmá tó dáná sun ọmọ, aya ọmọ àti ọmọ-ọmọ méjì jáde láyé
, Duration 5,37
28 Ẹrẹ̀nà 2023
Ìṣájú
Page
5
nínú
14
1
2
3
4
5
6
7
8
14
Tókàn