BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Aipe Ara
9:12
Fídíò,
"Ọ̀mùtí kọlù mí lọ́mọ ọdún mẹ́rin, mo di ẹlẹ́sẹ̀ kan àmọ́ kò dí mi lọ́wọ́ láti kàwé di dókítà"
, Duration 9,12
20 Owewe 2021
7:18
Fídíò,
Mo tọrọ ikú pẹ̀lú májèlé torí wàhálà ọkọ́ àmọ́ Ọlọ́run kò fún mi - Onírú tí kò ríran
, Duration 7,18
12 Ògún 2021
Inú mi dún, mo sì dúpẹ́ lọ́wọ́ àwọn ọmọ Nàìjíríà fún nǹkan ti mo da- Mary Daniel
17 Agẹmo 2021
7:31
Fídíò,
Ọ̀pọ̀ ọ̀rẹ́ àti aya lọ lẹ́yìn ti ojú mi lọ ní 2012 ṣùgbọ́n lónìí iṣẹ́ Àdìrẹ ti sọ mi dí eèyàn- Muritala David
, Duration 7,31
31 Èbibi 2021
4:27
Fídíò,
Kéèyàn fẹ́ pa ẹ̀fọn tàbí fẹ́ lé eṣinṣin lẹ́sẹ̀ kọ́wọ́ rẹ̀ má tó ó tàbí kó má lè dá dìde - Fatimah Aderounmu
, Duration 4,27
26 Èbibi 2021
4:54
Fídíò,
Ìrètí wà fún ọmọ tó jẹ́ ‘Down Syndrome’, wò ó bí wọn ṣe ń kọ́ iṣẹ́ ọwọ́
, Duration 4,54
20 Èbibi 2021
3:07
Fídíò,
Ẹ fún wa láṣẹ́ láti yọ ojú yín tẹ bá kú fún ìwúlò alààyè tí ojú rẹ̀ fọ́ - Ibùdó ìtọ́jú ojú ń pariwo
, Duration 3,07
30 Ìgbé 2021
2:16
Fídíò,
"Ìpèníjà ojú ló mú mi ṣe fíìmù nípa ọmọdé afọ́jú lọ́mọ ọdún méjìlá"
, Duration 2,16
25 Ìgbé 2021
Obìnrin ẹlẹ́sẹ̀ kan tó ń kirí omi rí àánú gbà lọ́wọ́ ìjọba Eko
13 Ìgbé 2021
Kí ló mú omijé jáde lójú Lateef Adedimeji?
13 Ìgbé 2021
7:54
Fídíò,
Mo di afọ́jú lẹ́yìn oṣù mẹ́ta tí aya mi kú lọ́jọ́ ìkúnlẹ̀ - Wòlíì Oluwalogbon
, Duration 7,54
14 Ẹrẹ̀nà 2021
6:40
Fídíò,
'Wọ́n ní kí n fún Faiza ní màjélè, abiyamọ ni mí, tí Ọlọ́run ò bá mú u lọ, mi ò ní pa á'
, Duration 6,40
25 Èrèlè 2021
6:16
Fídíò,
Wo tọkọ-taya tó ní ìpèníjà ojú àmọ́ tó ń ṣiṣẹ́ ọwọ́
, Duration 6,16
15 Sẹ́rẹ́ 2021
Ìdí rèé táwọn àkàndá ẹ̀dá fi dí iwájú iléeṣẹ́ ìjọba ìpínlẹ̀ Oyo pa l'Agodi n'Ibadan
7 Ọ̀pẹ̀̀ 2020
Sójà obìnrin lù mí lálù bami nílùú Ibadan
4 Ọ̀pẹ̀̀ 2020
2:08
Fídíò,
Ẹ̀gbọ́n mi tán ìṣòro mi nípasẹ̀ ṣíṣe ẹ̀ya ara àtọwọ́dá fún mi- Ubokobong Sunday
, Duration 2,08
1 Bélú 2020
8:06
Fídíò,
Ẹ wo tọkọtaya tí kò ríran amọ́ tí wọn jẹ́ olùkọ́
, Duration 8,06
19 Ọ̀wàrà 2020
5:04
Fídíò,
Olè fẹ́ fipá bá ìyá mi lòpọ̀, mo takú, wọ́n sì fìdí ìbọn fọ́ mi lójú - Ayàwòrán olójú kan
, Duration 5,04
7 Owewe 2020
6:59
Fídíò,
Ìpèníjà ojú kò ní kí ń má ṣiṣẹ́ ‘DJ’ - Etu Sodiq Omotayo
, Duration 6,59
17 Ògún 2020
5:49
Fídíò,
Mo fẹ́ pa ara mi nígbà tí ariwo orin níbi ìnáwó kan sọ mí di adití - Kemi Dairo
, Duration 5,49
7 Agẹmo 2020
Ìjọba fi páńpẹ́ ọba mú àwọn àkàndá tó fẹ̀họ́nú hàn ní Eko
26 Èrèlè 2020
Ìjọba Eko sọ pé ká má tọrọ bárà mọ́, wọ́n tún fòfin de kẹ̀ẹ̀kẹ́ tá a fi n ṣiṣẹ́ - Àwọn àkàndá ẹ̀dá
7 Èrèlè 2020
2:42
Fídíò,
'Ojú inú mi ni mo fi ń rí àwọn irinṣẹ́ tí mo fi ń ṣe mọkálíìkì'
, Duration 2,42
11 Sẹ́rẹ́ 2020
3:29
Fídíò,
'Ó lójú ìbi tí mo lè rìn sí ládùúgbò tórí irú ọmọ tí mo bí'
, Duration 3,29
3 Sẹ́rẹ́ 2020
Ìṣájú
Page
3
nínú
4
1
2
3
4
Tókàn