Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Mi ò gba kobo ní gbogbo ọ́dún mẹ́jọ mi gẹ́gẹ́ bíi gómìnà ìpínlẹ̀ Osun - Aregbesola

  2. Wọ́n ní ọkọ̀ bàálù NAF tó mú ẹ̀mí ọmọ mi lọ l'Abuja ti lo ọdún 49 láyé - Bàbá Flight Sergent Olasunkanmi

  3. Ẹ leè bẹ̀rẹ̀ sí ni gba afárá Third mainland Bridge padà báyìí, ó ti di ṣísí - Fasola

  4. Ọta ìbọn bá ọmọ mi àtọmọ mọ̀lẹ́bí mi lójú mi, ìtara ló ń tá mi lọ́wọ́ tí mọ́tò gbá èmi náà - Aráàlú Ibarapa

  5. Mi ò ní ri ẹni wà mọ́ mi, pè mi, fún mi lówó mọ́! Ó ṣe jẹ́ ọmọ mi ló m'órí ko - Ìyá Olasunkanmi Olawunmi

  6. Ṣẹ lóòtọ́ ni pé ìgò ni wọ́n gún pa olóògbé Ayinla Omowura? Àwọn ọmọ bàbá sọ òtítọ́ ibẹ̀ jáde

  7. Ṣé ẹ ti gbọ́ nípa òògùn ìbílẹ̀ Coronavirus tí Ooni filọ́lẹ̀? Ó ní ẹgbẹẹgbẹ̀rún èèyàn tó ní Covid-19 ló ti gbádùn

  8. Wo ìlú márùn-ún tó ń bọ tàbí sin ejò bí ọlọ́run, ṣé ìlú rẹ̀ wà lára wọn tí o kò mọ̀?

  9. Kí ló ṣe ọkùnrin yìí tó dédé ń sá lọ láàrin ìgboro ní ìhòhò ọmọlúàbí?

  10. Kí ni ìtumọ̀ pé Mide Funmi Martins kò sí níbi tí Damilare àti Shina Peters ti parí ìjà?

  11. Mo ṣèlèrí láti ṣa ipá mi fún ìpínlẹ̀ Ondo ní sáà kejì - Rotimi Akeredolu

  12. Ọ̀pẹ́lọpẹ́ àwọn tí kò dá a dá àwa onílé nìkan, kò bá ti ràn mọ́ ilé epo - Ará àdúgbò Oyemekun

  13. Àdó olóró ẹgbẹ́ agbésùnmọ̀mí sekú pa èèyàn mẹ́wàá ní Maiduguri, ọ̀pọ̀ farapa yána yàna

  14. Ìjọba orílẹ̀-èdè Oman fòfin de Nàìjíríà àti orílẹ̀-èdè Mẹ́sàn míràn lati má wọ ìlú wọn

  15. Mo ń ṣe ẹ̀tọ́ mi fún Damilare lọ́dọ̀ màmá àgbà, àmọ́ ǹkan tí ẹ kò mọ̀ nípa ọ̀rọ̀ yìí ló pọ̀ - Mide-Funmi Martins

  16. Ọlọ́pàá ò pe àwọn olóyè Ifon nítorí màálù tó kú, a fẹ́ gbọ́ tẹnu wọn lásán ni - Agbẹnusọ Ọlọ́pàá

  17. Kí ló ń gbé Rochas Okorocha lọ ilé ẹjọ́ lónìí?

  18. Mo faramọ kí ìjọba àpapọ̀ ta àwọn ohun ìní Naijiria kan - Atiku

  19. 'Àṣẹ ni! Gbogbo àgbàlagbà gbúdọ̀ gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 ṣáájú 31 July'

  20. Bí ẹranko igbó ṣe bu ìdí obìnrin kan tó ń bẹ̀rẹ̀ yàgbẹ́ jẹ