Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n
Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.
Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́
Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo
Wo àwọn ìpínlẹ̀ Yorùbá tó ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 ní Nàìjíríà
Bí ìjọba, ọlọ́pàá, ológun, Amotekun ò bá le gbà wá, àwa mú Wakili láti gba ìran Yorùbá sílẹ̀ ni - OPC
Wakili jiyàn ọ̀rọ̀, ó ní òun kò mọ ohunkohun nípa ìṣekúpani tó ń wáyé n'Ibarapa méjèèje
Nkán ìbànújẹ ni bí ọlọ́pàá ṣé ti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ OPC mọ́lé nítorí Wakili- Adari OPC
'Ọkọ̀ ńlá méjì ló kó àwọn Fulani wọ Ajowa Akoko ní Ondo, àmọ́ a ti jọ ń sọ̀rọ̀ pé ...'
Kí nìdí tí gbajúgbajà òṣèré Sotayo Gaga ṣègbéyàwó bóńkẹ́lẹ́?
Kò rí bákan lára ààrẹ o! Déédé ni abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 rí lára ààrẹ Buhari - Femi Adesina
Ta ni Ousmane Sonko, tí wàhálà bẹ́ sílẹ̀ ní Senegal lẹ́yìn tí ìjọba fòfin mú u?
Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọlọ́mọ mẹ́jọ ká nítorí pé ọkọ rí àwọn òbí ìyàwó fín
Wo ohun mẹ́fà tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìbọn AK-47
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó ń ṣe ayédèrú abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19
Wòlíì Kasali gba Bunmi ìyàwó rẹ̀ àkọ́fẹ́ padà, ìjà parí!
Wo ibi tí o ti lè fi orúkọ síìmù rẹ sílẹ̀ tàbí gba nọ́mbà tuntun tí síìmù rẹ bá sọnù
Àwọn òṣìṣẹ́ Shoprite bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn ní Ibadan, Akure, Eko àtàwọn ìlú míràn
Abẹ́rẹ́ àjẹsára, Covid 19 ti balẹ̀ bàgẹ̀ sí orílẹ̀èdè Naijiria
Ẹ wo èrò àwọn ènìyàn lórí bí Gòmìná Akeredolu ṣe fòfin de NURTW, RTEAN nípínlẹ̀ Ondo
Ọkùnrin méjì dèrò àhámọ́ lẹ́yìn tí wọ́n fipá bá ọmọ ọdún 16 lòpọ̀
Èèyàn méje móríbọ́ lẹ́yìn tí àwọn ajínigbé àtàwọn ọdẹ ìlú rọ òjò ìbọn fún ara wọn l'Ondo
Covid 19 lẹ́yìn ọdún kan ní Náìjíríà, ẹ̀kọ́ wo lẹ́yin rí kọ́?
