You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Agbébọn kọlu àwọn àgbẹ̀ abúlé Owode-Ketu àti Ijoun ní Ogun, èèyàn méjì fàyà gbọta

  2. Ẹnikẹ́ni tó bá dàgboro rú lórúkọ ìwọ́de #EndSARS, aò ní fọwọ́ kékeré mú o - Lai Mohammed

  3. Wo nkan tó yẹ́ kí o mọ̀ nípa gbajúmọ̀ oníwàásù 'Lórí irọ́'

  4. Wo ojú àwọn tí ọwọ́ tẹ̀ níbi ìkọlù NURTW ní Obalende

  5. Abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 ń yí àwọn èèyàn sí oníbálòpọ̀ akọsákọ àti abosábo - Alfa Abbas

  6. Ta ló ṣekúpa akẹ́kọ̀ọ́ iléèwé Poly Rufus Giwa tí wọ́n ṣá pa

  7. Lẹ́tà mi sí ààrẹ Buhari lóríi àwọn adári tó gba Fulani láàyè ní Nàìjíríà - Oluwo ti Iwo

  8. Bàyìí ni Yisa Sofoluwe, agbábọ́ọ̀lù Super Eagles tẹ́lẹ̀ ṣe jà jà lórí àìsàn kó tó dágbéré fáyé

  9. Ta ló ń kẹ̀yìn àwọn ọ̀dọ́ Nàìjíríà sírawọn lóríi àá ṣì Lekki toll gate, a ò ṣí i?

  10. Ṣé o mọ oríkì ìlú ara rẹ tó olùkọ́ yìí tó dántọ́ lẹ́nu rẹ̀ bíi ọmọ ìlú rẹ?

  11. Ìjọba Oyo bẹ̀rẹ̀ ìtọjú àwọn èèyàn tó farapa nínú ikọlù darandaran ní Ibarapa

  12. Ọlọ́pàá dá ọkùnrin méjì tó ń ní ìbálòpọ̀ ọkùnrin sọ́kùnrin padà sí ìlú abínibí wọn

  13. À ṣé ara mi ni isó tí ń rùn, tí èmi náà ń ṣépè fún ẹni tí Jamiu Azeez ń sọ - Mama Ereko

  14. Wo ohun tí Adájọ́ ṣe sí àṣùwọ̀n ìfowópamọ́sí Wòlíì Sotitobire

  15. Bí àjọ́ WHO ṣe wẹ Nàìjíríà yán kàn-kàn lára àwọn orílẹ̀èdè tí kò lẹ́tọ̀ọ́ sí abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19

  16. Irú ìkọlù wo ló ń wáyé ní Osun tí ìjọba fi kéde òfin kónílé-ó-gbélé 24 hours?

  17. Ẹ wo ìgbà mẹ́rin tí Ààrẹ Buhari ti tàpá sí òfin orílẹ̀-èdè Nàíjíríà

  18. Awakọ̀ ojú pópó láti Eko san N26,000 nítorí ó lu òfin tó de ìtànkálẹ̀ ààrùn Covid-19 - FRSC

  19. Remilekun Fatolu bú sẹ́kún fún ohun tó ti pàdánù láyé torí ọyàn ńla rẹ̀.

  20. Ìjọba ìpínlẹ̀ Eko ti f'òfin de ìpéjọpọ̀ tó bá ju àádọ́ta (50) èèyàn lọ torí ọwọ́jà kejì coronavirus