You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ààrẹ Trump pe òṣìṣẹ́ ìdìbò ní Georgia pé ko 'wa'ìbò láti dojú ìbò tó gbé Biden wọlé dé

  2. ''Ìròyìn òfegè lásán ni! Tinubu kò lùgbàdí coronavirus''

  3. Covid-19: ìjọba Nàìjíríà ti gbé nọ́mbà ìwé ìrìnà àwọn arìnrìn àjò ti 100 ti wọ́n fòfin de jáde

  4. Ọ burú jáì kí ààrẹ orílẹ̀èdè kọ̀ láti bá aráàlú sọ̀rọ̀ lásìkò ìṣòro - Ibrahim Babangida

  5. Mọ̀ si nípa Samuel Ajayi Crowther, bó ṣe pé àádóje ọdún tó jáye láyé

  6. Taa ni ọmọbìnrin Naijiria ẹni ọdún 26 tí Joe Biden yàn sípò olùbádámọ̀ràn lórí Covid-19 ní America?

  7. Aláìnímọ̀ ló ní kò sí àsọtẹ́lẹ̀ nínú Islam - Sabitu Olagoke

  8. Ìsìn àìṣùn ọdún kò ní kí ọdún yabo láì ní ìpinnu tàbí ètò f'ọ́dún tuntun - Pásítọ̀ Ajifowowe

  9. Àwọn àjàkálẹ-àrùn tó ti wáyé rí ṣáájú Coronavirus

  10. Ta ni Ọ̀jọ̀gbọ́n àkọ́kọ́ nípa ìmọ̀ ọ̀daràn ní Nàíjíríà, Femi Odekunle tí Covid-19 pa?

  11. Àkójọpọ̀ àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó dára àti èyí tó burú tó wáyé ní 2020

  12. Saheed tí wọ́n dáná sun ní OkeAdo, Ibadan, ajínigbé ni àbí àrìnfẹsẹ̀sí?

  13. Ẹ wo àwọn ìlúmọ̀ọ́ká ọmọ Nàíjíríà tó jáde láyé lọ́dún 2020

  14. Ètùtù bẹ̀rẹ̀ lẹ́yìn ìpapòdà Ọwá ìlú Ìgbájọ

  15. Kí ló fa gbas-gbos láàrín Davido àti Burna boy lórílẹ̀èdè Ghana?

  16. Ẹ̀ lajú yín, ayédèrú ìwé ẹ̀rí àyẹ̀wò COVID-19 gbòde kan l‘Eko - Ìjọba figbe ta

  17. Wọ́n gún ọkùnrin kan lọ́bẹ pa torí ó tako yínyin báńgà sínú Mọ́ṣálásí

  18. Ìjọba kéde ọjọ́ tuntun fún ṣíṣí afárá Third Mainland Bridge

  19. Àwọn àṣà tó milẹ̀ lọ́dún 2020 pẹ̀lú ìtàn lórí bí wọ́n ṣe jáde

  20. Allwell Ademola sọ̀rọ̀ lórí ìdí tó fi ń ṣe ọjọ́ ìbí 35 lọ́dọọdún