You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Ẹ wo àwòrán ìwọ́de àwọn ọmọ ẹgbẹ́ òṣìṣẹ́ káàkiri Nàìjíríà lórí ọrọ owó oṣù tó kéré jùlọ

  2. Wo àwọn ìpínlẹ̀ Yorùbá tó ti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 ní Nàìjíríà

  3. Bí ìjọba, ọlọ́pàá, ológun, Amotekun ò bá le gbà wá, àwa mú Wakili láti gba ìran Yorùbá sílẹ̀ ni - OPC

  4. Wakili jiyàn ọ̀rọ̀, ó ní òun kò mọ ohunkohun nípa ìṣekúpani tó ń wáyé n'Ibarapa méjèèje

  5. Nkán ìbànújẹ ni bí ọlọ́pàá ṣé ti àwọn ọmọ ẹgbẹ́ OPC mọ́lé nítorí Wakili- Adari OPC

  6. 'Ọkọ̀ ńlá méjì ló kó àwọn Fulani wọ Ajowa Akoko ní Ondo, àmọ́ a ti jọ ń sọ̀rọ̀ pé ...'

  7. Kí nìdí tí gbajúgbajà òṣèré Sotayo Gaga ṣègbéyàwó bóńkẹ́lẹ́?

  8. Kò rí bákan lára ààrẹ o! Déédé ni abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 rí lára ààrẹ Buhari - Femi Adesina

  9. Ta ni Ousmane Sonko, tí wàhálà bẹ́ sílẹ̀ ní Senegal lẹ́yìn tí ìjọba fòfin mú u?

  10. Ilé ẹjọ́ tú ìgbéyàwó ọlọ́mọ mẹ́jọ ká nítorí pé ọkọ rí àwọn òbí ìyàwó fín

  11. Wo ohun mẹ́fà tó yẹ kí o mọ̀ nípa ìbọn AK-47

  12. Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ àwọn tó ń ṣe ayédèrú abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19

  13. Wòlíì Kasali gba Bunmi ìyàwó rẹ̀ àkọ́fẹ́ padà, ìjà parí!

  14. Wo ibi tí o ti lè fi orúkọ síìmù rẹ sílẹ̀ tàbí gba nọ́mbà tuntun tí síìmù rẹ bá sọnù

  15. Àwọn òṣìṣẹ́ Shoprite bẹ̀rẹ̀ ìfẹ̀hónúhàn ní Ibadan, Akure, Eko àtàwọn ìlú míràn

  16. Abẹ́rẹ́ àjẹsára, Covid 19 ti balẹ̀ bàgẹ̀ sí orílẹ̀èdè Naijiria

  17. Ẹ wo èrò àwọn ènìyàn lórí bí Gòmìná Akeredolu ṣe fòfin de NURTW, RTEAN nípínlẹ̀ Ondo

  18. Ọkùnrin méjì dèrò àhámọ́ lẹ́yìn tí wọ́n fipá bá ọmọ ọdún 16 lòpọ̀

  19. Èèyàn méje móríbọ́ lẹ́yìn tí àwọn ajínigbé àtàwọn ọdẹ ìlú rọ òjò ìbọn fún ara wọn l'Ondo

  20. Covid 19 lẹ́yìn ọdún kan ní Náìjíríà, ẹ̀kọ́ wo lẹ́yin rí kọ́?