You’re viewing a text-only version of this website that uses less data. View the main version of the website including all images and videos.

Take me to the main website

Akẹ́kọ̀ọ́ FGC Yauri mẹ́ta pàdánù ẹ̀mí wọ́n nígbà t'awọn ológun àti ajínigbe kojú ará wọ́n

Awọn to ba BBC sọrọ sọ pe ninu ikọlu to waye laarin awọn agbebọn yi ati ọmọogun Naijiria ni awọn ọmọ yi ti padanu ẹmi wọn.

Ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ tí ń lọ lọ́wọ́

Yetunde Olugbenga and Yemisi Oyedepo

  1. Àwọn olóṣèlú gbọdọ̀ máa fi Ògún búra, bí Nàìjíríà bá fẹ́ dẹ́kun ìwà àjẹbánu - Guru Maharaj ji

  2. Wo obìrin méjì tó ń fi ìbásùn inú yìyín "Snow" ṣara rindin kí ọlọpàá tó ká wọn

  3. Àwa ìpínlẹ̀ fúnra wa ló yẹ ká máa ṣàkóso inú igbó wa - Àfẹnukò àwọn gómìnà àti àwọn Ọba Yorùbá

  4. Ikú Ọ̀mọ̀we Fatai Aborode tí wọ́n pa ní Ibarapa lọ́wọ́ òṣèlú nínú - Makinde

  5. Okùnrin ẹni ọdún 73 fi ìyàwó rẹ̀ ọdún mẹ́rìndínlógún sílẹ̀ lẹ́yìn tó lóyún ìbẹta

  6. Ìgbìmọ̀ ìwádìí ìfìyajẹni ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Eko fún ẹbí méjì ní ₦10m ẹnì kọ̀ọ̀kan

  7. Ọwọ́ pálábá Abubakar, mọ́káliíkì ségi níbi tó ti fẹ́ jí ọkọ̀ gbé l'Abuja

  8. Ìjọba Naijiria buwọ́lu abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 fún lílò

  9. A kò tíì gbọ́ pé ilé ẹjọ́ wọ́gilé gbígba owó lọ́wọ́ àwọn dẹ́rẹ́bà ni ibudokọ ipinlẹ Oyo- awọn Awakọ̀

  10. Akẹ́kọ̀ọ́ ọmọ ọdún mẹ́rìnlá mú ìbọn ìléwọ́ lọ ilé ìwé láti yìín lu olùkọ́ tó ní kó gé irun orí rẹ̀

  11. Ṣé lóòtọ́ ni omidan yìí ya wèrè ní kété tí ọ̀rẹ́kùnrin rẹ̀ ní òun fẹ́ fi ṣaya?

  12. Gbenga Daniel kò ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní PDP, ó kàn fi ẹ̀ka APC kan sílẹ̀ lọ sí òmíràn ni- PDP

  13. A fẹ́ kí ìjọba fòfin de àwọn darandaran tó máa ń fi ìbọn Ak47 da málúù láàrín ìlú- MURIC

  14. Ọbalayé tó kéré jùlọ nílẹ̀ Yorùbá, Oloyede Akinghare gbadé

  15. Agbaṣẹ́ṣe jẹ búlálà méjìlá lẹ́yìn tó jí ẹ̀rọ ìbáraẹnisọ̀rọ̀

  16. Àyè wà fún àwọn Fulani tí kíì ṣe ọ̀daràn láti wá fi ilú Iwo ṣebùgbé - Oluwo

  17. Nigeria Army recruitment 2021: Ẹ wo bí ẹ ṣe lè darapọ̀ mọ́ iléeṣẹ́ Ọmọogun Nàìjíríà

  18. Ṣé ìyàwó ilé tàbí àlè níta ló yé kí ọkùnrin lo 'Valentine' rẹ̀ pẹ̀lú?- Mercy Aigbe

  19. Ìjọba Nàìjíríà tó yé kó pèsè aàbò ló kùnà lẹ́nú ojúṣe wọn- Mr Macaroni lẹ́yìn tó ti àtìmalé dé

  20. Ta ni dókítà, ọmọ Ghana tó fi iṣẹ́ abẹ gba obìnrin tó lẹ́ 'gorilla glue mọ́ irun orí sílẹ̀?