Kò ṣeé má gbọ̀ọ́
Gbogbo eto lo ti to bayiii
Fun kinni?
Fun iwọde ti ẹgbẹ oṣiṣẹ NLC fẹ ṣe lọla ọjọ Iṣẹgun tako afikun ida aadọta owo tariiifu ori ipe ati data ori foonu
Ṣaaju ni ẹgbẹ oṣiṣẹ ti kede igbesẹ yii nibi ipade igbimọ alaṣẹ ti wọn ṣe nipari oṣu to lọ l'Abuja.
ẹkunrẹrẹ wa lori ikanni BBC Yoruba
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ọmọ Naijiria, ẹ mura silẹ o
Mura silẹ fun ki tun ni?
Ijọba apapọ lo ti kede pe oun yoo ṣe afikun owo tariifu ina mọnamọna laipẹ
ṣebi lọdun to lọ ni wọn kede afikun owo tariifu kan ni?
Bẹẹ ni amọ Kan soju BC.Com/Yoruba fun idi abajọ afikun ti wọn ṣẹṣẹ fẹ sẹ yii
''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''''
Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti sọ pe awọn ti bẹrẹ iwadii lori fidio
to lu ori itakun ayelujara pa eyi to ṣafihan bi afurasi kabiyesi kan ṣe n fiya jẹ ọkan lara awọn oloye rẹ
Bi ori ade naa ti n ṣepe nla nla ninu fidio ọhun ni ẹnikan n fun oloye naa ni igbaju ati igbamu
Fun ẹkunrẹrẹ iroyin yii....





























