Alákóso ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ nígbàkanrí, Adetunji Olurin jáde láyé

Published

Alakoso ijọba ologun ni ipinlẹ Ọyọ nigbakan ri, Ọgagun Adetunji Idowu Olurin ti jade laye.

Olurin to tun figbakan ri ṣe alakoso alagbada ni ipinlẹ Ekiti nigba kan ri jade laye lẹni ọdun mejidinlọgọrun.

Ileewosan ẹkọṣẹ iṣegun fasiti ilu Eko (LUTH)

Ọms ilu Ilaro ni Ọgagun Olurin, o si kẹkọ ologun ni ile ẹkọṣẹ ogun ti ilẹ Naijiria, NDA ni Kaduna laarin ọdun 1967 si 1970, ileewe ẹkọṣẹ ologun School of Infantry, Quetta Pakistan lọdun 1973, ileẹkọ awọn lọgalọga lẹnuṣẹ ologun ni Naijiria, Army command and Staff college, ni ilu Jaji laarin ọdun 1977 si ọdun 1978.