EKIFEST 2019: Ẹkẹ mímù, ayò títa, àfihàn iṣẹ́ ọnà wáyé níbi àjọ̀dún àṣà

Published
"Ẹni ba laya, ko wa wọọ, maa lu ẹ bolẹ"- Ta ni yoo bori laarin awọn mejeeji?

Ọna wo ni maa gba fi ẹyin ọkunrin yii janlẹ ni ikọọkan awọn amuẹkẹ yii n sọ.

Alaye ree lori bi idije ẹkẹ mimu naa yoo ti waye.

Orin ‘ ẹ jade, kẹ wa wo wa lawọn ọmọde onijo ibilẹ yii n kọ.

Asọ oke ni asọ ibilẹ wa nil Yoruba, awọn ọna ti a n gba hun asọ oke ree

Ounjẹ lọrẹ awọ, ounjẹ to dara lo n se ara loore

Ebi kii wọnu, ki ọrọ miran wọọ. Awọn oniruuru eroja ounjẹ ati awọn ikoko abalaye ta fi n dana ree.

Awọn afihan isẹ ọna to jẹ oju ni gbese ree nibi ajọdun asa ni Ekiti.

Ẹ jẹ ka gbedi fun awọn onisẹ ọna yii fun isẹ ribiribi ti wọn se, aworan gomina Kayode Fayemi ati iyawo rẹ ree.

Ero maa wa, ero maa bọ, ajọdun asa lo n lọ lọwọ yii, ero maa wa.
























