Ààrẹ Morsi orílè-èdè Egypt dákú,o gbà bẹ d'ero Alakeji

Aworan aarẹ Morsi

Oríṣun àwòrán, Getty Images

Published

Aarẹ tẹlẹ ri orileede Egypt Mohammed Morsi, ti awọn ologun yọ loye lọdun 2013 ti fo sanlẹ ku ninu ile ẹjọ gẹgẹ bi oun ti ile iṣẹ amounmaworan ilẹ naa kede.

Iroyin naa ni ibi ti aarẹ naa ti n dahun ibeere lo ti kọkọ daku gbọnrangandan ki o to di pe o gba ibẹ lọ alakeji

Ẹni ọmọ ọdun mẹtalelọgọta nii ṣe

A o maa mu ẹkunrẹrẹ iroyin naa wa fun yin laipẹ.