Koko iroyin: Ìjọ Àgùdà ni ẹ̀jẹ̀ pọ̀ ní Nàíjíríà, Àwọn asòfin gbára wọn lẹ̀sẹ́ l‘Ondo
Published
Eyi ni awọn akojọpọ iroyin ti toni.
Ìjọ Àgùdà ni kò dára ká máa ké gbàmí-gbàmí kiri lójoojúmọ́
Àwọn ọmọ ìjọ Àgùdà ní ìlú Èkó se ìwọ́de ní ọjọ́ ìsẹ́gun pé kí ìjọba tètè fòpin sí ìwà ìsekúpani tó ń wáyé ní ojoojúmọ́.
Ilé asòfin Ondo: Olórí di méjì láàrin ọjọ́ kan soso

Oríṣun àwòrán, @jollofricejim
Awọn asofin ipinlẹ Ondo ti fi ija pẹẹta ni Ile Igbimo Asofin ipinlẹ naa, lẹyin ti awọn asofin di ibo lati yọ Igbakeji olori Ile Asofin, Iroju Ogundeji.
Iroyin sọ wi pe, ọkan lara wọn ju ẹsẹ lu igbakeji abẹnugan ti wọn yo ọ nipo naa. Ẹ ka ẹkunrẹrẹ nibi
Awọn nkan miran ti ẹ ni lati mọ loni
Gbọ iroyin iṣẹju kan BBC
Fidio wa fun toni
'Kò sí ǹkan tí ọwọ́ ọ̀tún ń se tí ọwọ́ òsì kò lè se'


























