BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
ifiya jẹni labẹ ile
Àwọn ààfáà faraya níbi àdúrà Fìdáù Yetunde tí wọ́n ní ààfáà kan ṣekúpa n'Ilorin
16 Èrèlè 2025
Kóòtù yọ̀ǹda ọkùnrin tó fi ìbálòpọ̀ pa ìyàwó rẹ̀, ariwo ta
16 Èrèlè 2025
2:53
Fídíò,
'Àwọn ọkọ, mọ̀lẹ́bí ló ń ṣokùnfà ikú ọ̀wọọ̀wọ́ àwọn obìnrin lọ́dọọdún'
, Duration 2,53
7 Èrèlè 2025
"Orí mi lọkọ mi fẹ́ẹ́ bẹ́ dànù tẹ́lẹ̀, mo fi ọwọ́ gba ọ̀bẹ ló fi gé mi lọ́wọ́ méjéèjì"
29 Sẹ́rẹ́ 2025
Lẹ́yìn ìfipábánilòpọ̀ márùn-ún tó kojú, Iyabo Ojo ní òun kò ní í sinmi ogun pẹ̀lú àwọn afipábánilòpọ̀
5 Sẹ́rẹ́ 2025
Ọkùnrin tó dáná sun ara rẹ̀ àti ìyàwó l'Ondo jáde láyé, ìyàwó dèrò ilé ìwòsàn
15 Ọ̀pẹ̀̀ 2024
Bamidele f'ọwọ̀ tẹ ọyán, ló bá rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́wàá he
12 Ọ̀pẹ̀̀ 2024
Arákùnrin tó fẹ́ fi ìyá rẹ̀ ṣe ògùn owó fi májèlé sí oúnjẹ pa ìyá rẹ̀, ìyá-ìyá rẹ̀, àbúrò ìyá rẹ̀ obinrin àti ọmọ rẹ̀
29 Bélú 2024
'Àwọn ọ̀gá mi tì mi mọ́lé làsìkò ogun, wọ́n sá lọ ní tiwọn'
12 Ọ̀wàrà 2024
Mọ̀ nípa Ogunnaike, afurasí apànìyàn tó ní kí iléejọ́ fún òun l'óúnjẹ kí wọ́n tó pa òun
8 Ọ̀wàrà 2024
Àwọn ọkùnrin mẹ́rin tó páwọpọ̀ fipá bá ọmọbìnrin kan lòpọ̀ rí ẹ̀wọ̀n gbére he
1 Ọ̀wàrà 2024
Ẹ̀yin obìnrin tọ́kọ yín ń yan àlè, ẹ má kọkọ sílẹ̀ o, ìdí rèé tí ẹ fi gbọdọ̀ forí ti ìgbéyàwó yín - Toyin Tomato
25 Owewe 2024
Ọkùnrin tó yìnbọn fún ọkùnrin míì tó ká mọ́ orí ìbùsùn ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀, wọ gàù
5 Owewe 2024
"Èmi àti ọkọ mi dìjọ jẹun alẹ́, ta ayò papọ̀ àmọ́ ó kọlù mi lójú oorun, mo sì pàdánù ojú méjéèjì"
5 Owewe 2024
'Libya ni mo ti ríi tí ilé ọmọ èèyàn jáde síta tó dà bíì nylon'
9 Òkùdu 2024
Ìyàwó tuntun gé nǹkan ọkùnrin ọkọ rẹ̀ ní Kaduna
8 Òkùdu 2024
Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ fásiti Ajayi Crowther lu akẹgbẹ́ wọn pa nítorí fóònù, ohun tí a mọ̀ rèé
27 Èbibi 2024
Alfa dáná sun ilé ìyàwó rẹ̀ tó kọ̀ láti kírun pẹ̀lú rẹ̀ l’Ekiti
10 Èbibi 2024
Ìwọ́de gbòde ní Australia láti fòpin sí pípa àwọn obìnrin lọ́nà àìtọ́
29 Ìgbé 2024
Iléẹjọ́ ní kí wọ́n yẹgi fún ọmọ China tó ṣekúpa ọ̀rẹ́bìnrin rẹ̀ ọmọ Naijiria ní Kano
26 Ẹrẹ̀nà 2024
Ẹ̀yin ìyàwó, ẹ máa dákẹ́ fáwọn ọkọ yín tí ìjà bá ṣẹlẹ̀, Mínísítà rọ àwọn obìnrin
21 Ẹrẹ̀nà 2024
Ọkùnrin tó la orí ọmọ ọdún méjì mọ́ ògiri rí ẹ̀wọ̀n gbére he
17 Èrèlè 2024
Àlùbamí ni ọkọ mi tẹ́lẹ̀ máa ń lù mí tí Man United bá ti fìdírẹmi - Ìlúmọ̀ọ́ká òṣèbínrìnrin
30 Sẹ́rẹ́ 2024
Ọkùnrin kan gé orí ọmọge tí wọ́n jọ lọ sí hòtẹ́ẹ̀lì
20 Sẹ́rẹ́ 2024
Ìṣájú
Page
2
nínú
8
1
2
3
4
5
6
7
8
Tókàn