BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Ogun
Wo ewu tó rọ̀ ma kí wọn sin ọba tó ṣètùtù nílànà ẹ̀sìn Krìsítẹ́nì àti Islam
17 Ẹrẹ̀nà 2021
Wo ibùdó tó sún mọ́ ọ láti gba abẹ́rẹ́ àjẹsára Covid-19 l'Eko
17 Ẹrẹ̀nà 2021
Agbébọn pa èèyàn 58 tó ń ti ọjà bọ̀, jó ọ̀pọ̀ ọkọ̀, fi oúnjẹ ṣòfò
17 Ẹrẹ̀nà 2021
Àwọn panápaná ti pa iná tó ṣẹ́yọ nídàjí òní nílé epo NNPC ní Akute nitòsí Berger báyìí
6 Ẹrẹ̀nà 2021
Ọkùnrin méjì dèrò àhámọ́ lẹ́yìn tí wọ́n fipá bá ọmọ ọdún 16 lòpọ̀
2 Ẹrẹ̀nà 2021
13:38
Fídíò,
Ọta ìbọn bá ọmọ mi àtọmọ mọ̀lẹ́bí mi lójú mi, ìtara ló ń tá mi lọ́wọ́ tí mọ́tò gbá èmi náà - Aráàlú Ibarapa
, Duration 13,38
27 Èrèlè 2021
Àwa ìpínlẹ̀ fúnra wa ló yẹ ká máa ṣàkóso inú igbó wa - Àfẹnukò àwọn gómìnà àti àwọn Ọba Yorùbá
21 Èrèlè 2021
Alhaja Muslimot Salami tí àwọn darandaran kọlù ní Ogun tí padà jẹ́ Olorun nípè!
18 Èrèlè 2021
Gbenga Daniel kò ṣẹ̀ṣẹ̀ kúrò ní PDP, ó kàn fi ẹ̀ka APC kan sílẹ̀ lọ sí òmíràn ni- PDP
18 Èrèlè 2021
Àwọn darandaran gbẹ̀mí èèyàn mẹ́ta níjọba ìbílẹ̀ Ariwa Yewa lẹ́yìn àbẹ̀wò àwọn aṣojú ìjọba ní ìpínlẹ̀ Ogun
16 Èrèlè 2021
Agbébọn kọlu àwọn àgbẹ̀ abúlé Owode-Ketu àti Ijoun ní Ogun, èèyàn méjì fàyà gbọta
12 Èrèlè 2021
'' Ìrọ ní ò, N51.8million kọ́ ní àwọn Naijiria dá fún Sunday Igboho, N4milion ní''
5 Èrèlè 2021
Ǹkan tÍ Sunday Igboho ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun- Olórí Miyetti Allah ilẹ̀ Yorùbá
3 Èrèlè 2021
Ọlọ́pàá Ogun ké pe ẹni tó ni Pavillion Hotel láti wá ṣàlàyé ìdí tí kámẹ́rà fi wà nínú yàrá
2 Èrèlè 2021
1:04
Fídíò,
'Ǹkan tÍ Sunday Igboho Ṣe ní Ibarapa tún ti ṣelẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ogun'
, Duration 1,04
2 Èrèlè 2021
Ìjọba àpapọ̀ bẹ̀rẹ̀ sísan N20,000 owó ìrànwọ́ fáwọn obìnrin igbèríko l'Ogun
31 Sẹ́rẹ́ 2021
Abdullahi, Ẹni ọdún 52 rí ẹ̀wọ̀n he nítorí pé ó jí fóònù méjì gbé ní Abeokuta
31 Sẹ́rẹ́ 2021
Ìjọba Oyo, Ogun ké sí darandaran láti wá yá ilẹ̀ fún ọ̀sìn ẹran lọ́dún mẹ́ta-mẹ́ta
30 Sẹ́rẹ́ 2021
Ẹ múra mi sílẹ̀ ẹ̀yin apààyàn Fulani ní Ogun, mò ń bọ̀ kánkán - Sunday Igboho
28 Sẹ́rẹ́ 2021
Ọkọ̀ agbépo bẹ́ntiról kankan kò gbọdọ̀ gun afárá nípínlẹ Ogun mọ́ - Gomina Dapo Abiodun
20 Sẹ́rẹ́ 2021
Jubril Martins-Kuye ti jáde láyé
17 Sẹ́rẹ́ 2021
Gomina Sanwo-Olu sún ọjọ́ "ṣiṣẹ́ láti ilé" síwájú fún àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba
17 Sẹ́rẹ́ 2021
Ẹ wo ọba kan nílẹ̀ Yorùbá, tí kò ṣe ètùtù tàbí náwó ànájù, kó tó jọba
16 Sẹ́rẹ́ 2021
Ọlọ́pàá kò fẹ́ yìnbọn, kó má ba à ba aráàlú, l‘àwọn afurasí olóògùn olóró ba sá mọ́ wọn lọ́wọ́
15 Sẹ́rẹ́ 2021
Ìṣájú
Page
24
nínú
31
1
21
22
23
24
25
26
27
31
Tókàn