BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ipinlẹ Ogun
Àwọn ọlọ́jà figbe ta ní ìpínlẹ̀ Ogun lẹ́yìn tí wọ́n dòwòpọ̀ pẹ̀lú iléeṣẹ́ ayánilówó kan
22 Òkùdu 2023
Wo adarí ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin tuntun ìpínlẹ̀ Ogun, Oluomo àti ìgbákejì rẹ̀, Latifat
20 Òkùdu 2023
6:15
Fídíò,
'Ifá ló mú èmi o! Ẹnu iṣẹ́ Ọ̀jọ̀gbọ́n Fásitì ni mo wà tí wọ́n ní kí n wá jẹ Olota ti ìlú Ota'
, Duration 6,15
19 Òkùdu 2023
Àwọn Alfa sìnkú Ọba Gbagura nílànà ẹ̀sìn Islam, lẹ́yìn táwọn Aláwo ṣe ètùtù wọn
15 Òkùdu 2023
Ẹlẹ́gbẹ́ òkùnkùn tó bá ṣe ohunkóhun pẹ̀lú òkú mi yóò dara pọ̀ mọ́ mí lájùlé ọ̀run - Olubara
11 Òkùdu 2023
'Ìbínú ló jẹ́ kí n da omi gbígbóná lé ìyá "láńlọọ̀dù" mi lórí, ẹ ṣàánú mi'
8 Òkùdu 2023
5:02
Fídíò,
Nǹkan tí mo lè fi eyín dá lárà pọ̀ ju ti àgbọn lọ -Mayowa tó ń fi eyín gé àgbọn
, Duration 5,02
2 Òkùdu 2023
Iléẹjọ́ dá aṣòfin tó ń ṣójú ẹkùn Ìjẹ̀bú North II padà sípò lẹ́yìn tí wọ́n fòfin dèé
1 Òkùdu 2023
Owó oṣù: Àwọn òṣìṣẹ́ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ìpínlẹ̀ Ogun daṣẹ́ sílẹ̀
31 Èbibi 2023
Àwọn nǹkan mẹ́wàá tó yẹ kí o mọ̀ nípa Subomi Balogun tó dolóògbé nìyí
19 Èbibi 2023
Wo iye tí agbénipaṣètùtùọlà kan ń ta ẹsẹ̀ odindi èèyàn ní ìpínlẹ̀ Ogun
4 Èbibi 2023
Àwọn dókítà tún fún ìjọba àpapọ̀ Nàìjíríà ní gbèdéke tuntun, tàbí kí wọ́n gùn lé ìyanṣẹ́lódì
29 Ìgbé 2023
6:37
Fídíò,
Mo lo ọjọ́ mẹ́ta ní àhámọ́ àwọn ajínigbé, ojú mi rí tó
, Duration 6,37
24 Ìgbé 2023
Babaláwo so ọmọ rẹ̀ méjì mọ́lẹ̀, fi ebi pa wọ́n ku
20 Ìgbé 2023
12:40
Fídíò,
Mi ò lè wo òkú ọmọ mi, wọ́n ti gún un lọ́rùn yána-yàna; ọmọ Nàìjíríà ẹ gbà mi o!
, Duration 12,40
18 Ìgbé 2023
Òkú ẹni ọdún 86 pòórá ní “mortuary” bí mọ̀lẹ́bí ṣe wá gbèé fún ìsìnkú, wàhálà bẹ́ sílẹ̀!
17 Ìgbé 2023
Àwọn adigunjalè ṣọṣẹ́ ní ọjà fóònù l'Abeokuta, pa ọlọ́jà kan, jí fóònù tó tó N14m gbé lọ
14 Ìgbé 2023
Ènìyàn méje jóná nínú ìjàmbá ọkọ̀ márosẹ̀ Ibadan sí Eko
11 Ìgbé 2023
Torí Portable, aṣọ kanṣoṣo ni mò ń wọ̀ kiri fún ọjọ́ mẹ́ta – Stelliza
4 Ìgbé 2023
Àwọn ẹ̀sùn mẹ́fa tí Portable yóò jẹ́jọ́ lé lórí rèé – Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá
2 Ìgbé 2023
Ọwọ́ ọlọ́pàá tẹ ajínigbé méjì, àwọn tí wọ́n jí gbé gba òmìnira
25 Ẹrẹ̀nà 2023
Ẹ̀mí èèyàn mẹ́wàá míì tún bọ́ sọ́wọ́ àgbébọn ní Kaduna, ọ̀pọ̀ fara gbọta
13 Ẹrẹ̀nà 2023
Wo Bàbá tó tá ọmọ rẹ oṣù mẹjọ fún òníbara mẹ́ta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀
13 Ẹrẹ̀nà 2023
Ẹni tí mo ṣe lóore ló gún mi lọ́bẹ ní ọrùn, gún ẹ̀gbọ́n mi ní apá – Portable
13 Ẹrẹ̀nà 2023
Ìṣájú
Page
12
nínú
31
1
9
10
11
12
13
14
15
31
Tókàn