BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Kàdúná
Hajiya Binta Balarabe Kubaus rí ẹ̀wọ̀n ọdún mẹ́wàá he lẹ́yìn tó lu jìbìtì ₦5.5m
20 Sẹ́rẹ́ 2022
Àwọn agbébọn ti yìnbọn pa èèyàn 38 ní Kaduna
19 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Àwọn ajínigbé pa Pásítọ̀ kan, jí obìrin kan, ọmọ rẹ̀ mẹ́rin gbé lọ
12 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ọgọ́ta èèyàn tí àwọn jàndùkú jí gbé nínú ìjọ Baptist ní Kaduna ti gba ìtúsílẹ̀
5 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Àwọn agbébọn ṣèkọlù àdó olóró sí ojú irin Kaduna sí Abuja, orí ló kó wa yọ! - Shehu Sani
21 Ọ̀wàrà 2021
Láì sí ẹ̀kùn àríwá, òfo ní ìpínlẹ̀ Eko, Rivers lórí owó ọjà - Masari
20 Owewe 2021
Wọ́n tí dóòla ọmọogun Major Datong tí àwọn agbébọn jígbé lásìkò ìkọlù sí NDA
18 Owewe 2021
Àwọn jàndùkú jí Emir Bungudu gbé, wọ́n pa ọlọ́pàá lọ́nà mọ́rosẹ̀ Abuja sí Kaduna
15 Owewe 2021
Nǹkan yan! Ìrẹsì, Spaghetti àti sìgá làwọn agbébọn ń béèrè fún ìtúsílẹ̀ àwọn tí wọ́n bá jí gbé báyìí
11 Owewe 2021
Bí àṣìta ìbọn ṣe pa ọmọ ọdún 9 níbi ètò ìdìbò ìjọba ìbílẹ̀ ní Kaduna
5 Owewe 2021
Mo ní ẹ̀rí tó dájú pé àwọn Fulani fẹ́ gba gbogbo ilẹ̀ Nàìjíríà - Ortom
30 Ògún 2021
Ìkọlù tó wáyé ní ilé ẹ̀kọ́ ológun ní Kaduna le jẹ́ ète láti fi ìjọba Buhari ṣe ẹlẹ́yà - Garba Shehu
26 Ògún 2021
Ẹgbẹ́ ọmọ bíbí Gúúsù Kaduna ní ìkọlù àwọn agbébọn sí NDA kìí ṣe ìyàlẹ́nu
25 Ògún 2021
"Ó yẹ kí àwọn ẹ́ṣọ́ aláàbò lè mọ̀ pé àwọn jàndùkú fẹ́ kọlu ilé ẹ̀kọ́ ẹ̀kọ́ṣẹ́ ọmọogun Nàìjíríà, NDA kí ìṣẹ̀lẹ̀ náà tó wáyé"
25 Ògún 2021
Àwọn jàndùkú afẹ̀mí-ṣòfò ṣekúpa èèyàn 24 ní Kaduna àti Katsina lọ́jọ́ kan ṣoṣo
23 Ògún 2021
Àwọn ajínigbé tú àwọn ọmọ akẹ́kọ̀ọ́ Bethel mẹ́ẹ̀dọ́gún míràn sílẹ̀
22 Ògún 2021
Èèdì! Èdè-ài-yedè bẹ́ sílẹ̀ lórí owó pínpín, awọn ajínigbé yìnbọn pa ara wọn, èèyàn mẹ́sàn-án kú
21 Ògún 2021
5:49
Fídíò,
Àwọn ajínígbé tún ti tú akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin Bethel Baptist school míràn sílẹ̀ ní Kaduna
, Duration 5,49
1 Ògún 2021
Kí ni àwọn ẹ̀sun tuntun tí ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna tún gbé dìde tako Ibrahim El-zakzaky?
31 Agẹmo 2021
Pẹ̀lú omijé lójú làwọn òbí akẹ́kọ̀ọ́ 28 Bethel Baptist táwọn ajínigbé tú sílẹ̀ fi pàdé ọmọ wọn
25 Agẹmo 2021
Ìròyìn ayọ̀! Emir tí wọ́n jígbé ní Kaduna gba ìtúsílẹ̀, báwó ló ṣe ṣeé láàrin ọ́jọ́ méjì?
12 Agẹmo 2021
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kaduna kéde òní ọjọ́ Ajé gẹ́gẹ́ bíi ọjọ́ ìsinmi nítorí ikú ìgbákejì gómìnà Bantex tó dolóògbé
12 Agẹmo 2021
A ń gbóhùn àdúrà sókè ní orílẹ̀èdè 127 lágbàáyé torí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ Baptist tí wọ́n jígbé ní Kaduna -Baptist Convention
10 Agẹmo 2021
Ó tún ti ṣẹlẹ̀! Agbébọn tún jí àwọn ọmọ ilé ẹ̀kọ́ Baptist kan gbé
5 Agẹmo 2021
Ìṣájú
Page
4
nínú
6
1
2
3
4
5
6
Tókàn