BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ileesẹ Ologun
Òkú ọlọ́pàá tí àwọn ṣọ́jà pa pẹ̀lú ìbọn rẹ̀ ṣì wà pẹ̀lú wọn, wọn kò tíì gbé e fún wa -iléeṣẹ́ ọlọ́pàá Eko
5 Ògún 2022
Agbébọn pá èèyàn méje tó ń bọ̀ láti ayẹyẹ ìgbéyàwó
19 Agẹmo 2022
Àwọn àgbẹ̀ yarí fún ìjọba Ondo lórí bó ṣe ń ta ilẹ̀ oko wọn
18 Agẹmo 2022
Iléeṣẹ́ ológun òfurufú ṣèèṣì ju àdó olóró sí abúlé kan ní Katsina, ẹnìkan ku, eèyàn 13 farapa
8 Agẹmo 2022
Russia gbà pé òun lẹ́bi lórí ìkọlù Ukraine àmọ́ ó ní ojú kò tì òun
17 Òkùdu 2022
Nínú kí wọ́n kéde ikú mi àti kí n san owó ìdóòlà ₦100m tó takò ìjọba èwo lẹ fẹ́ kí n ṣe?
2 Òkùdu 2022
Ẹ̀rọ ayàwòrán CCTV ṣe àkọsílẹ̀ bí àwọn ọmọ ogun Russia ṣe pa aráàlú méjì ní Ukraine
14 Èbibi 2022
Ọwọ́ tẹ ọmọ ológun Nàìjíríà tó ń lẹ̀dí àpò pọ̀ pẹ̀lú ISWAP, wo bí o ṣé gbà ẹ̀mí ará rẹ̀
28 Ìgbé 2022
Àṣírí ayédèrú ológun méjìlá tó ń gbégi dínà ní Ajah ati agbègbè míì tú sọ́wọ́ iléeṣẹ́ ológun
14 Ìgbé 2022
Àkàrà tú sépo fún ayédèrú ọ̀gágun tó fi Khaki lú jìbìtì N266.5m
12 Ìgbé 2022
Wo àwọn àṣìṣe ikọ̀ ológun Russia ní Ukraine
19 Ẹrẹ̀nà 2022
Ológun ní kí aya mi bọ́ aṣọ kúrò lára, pa ọmọ mi mẹ́rin àtàwọn alátìlẹyìn mi - El Zakzaky
19 Ẹrẹ̀nà 2022
10:54
Fídíò,
Mo lo oṣù mẹ́ta ní àhámọ́ ológun àti DSS torí nọ́mbà Sunday Igboho tó wà lórí fóònù mi – Tula Oyo
, Duration 10,54
15 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọ̀rọ̀ yóò lẹ́yìn bí China bá ṣerànwọ́ fún Russia lórí ogun Ukraine - Amẹ́ríkà lọgun
14 Ẹrẹ̀nà 2022
EFCC gbẹ́sẹ̀lé dúkìá ọ̀gá olọgun tí iye rẹ̀ tó ₦10.9b
16 Èrèlè 2022
A ṣì lè yanjú ọ̀rọ̀ Ukraine ní ìtùbí-ìnùbí - Russia
15 Èrèlè 2022
Àjọ AU fajúro lórí ọwọ́jà ìdìtẹ̀ gbàjọba tó ń wáyé nílẹ̀ Afrika
7 Èrèlè 2022
Àwùjọ àgbáyé, ẹ ṣèrànwọ́ fún Burkina Faso kó le borí ìṣòro - Olórí ìjọba ológun
28 Sẹ́rẹ́ 2022
Kí ló dé tí ológun ń yẹ àga ìjọba mọ́ alágbádá nídìí l‘Áfíríkà?
26 Sẹ́rẹ́ 2022
Ìtàn ayé ọ̀gágun Paul-Henri Sandaogo Damiba tó léwájú ológun gbàjọba Burkina Faso?
25 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọkùnrin kan ná N20m tó ṣèèsi wọ inú àkáùǹtì rẹ̀, ó forí kó ẹjọ́
20 Sẹ́rẹ́ 2022
Nkan tó yẹ kí o mọ̀ nípa Bello Turji, afurasí bálógun ajínigbé ní Ariwa Naijiria
5 Sẹ́rẹ́ 2022
Ọmọ ogun orílẹ̀-èdè Myanmar ṣekúpa èèyàn 40, wọ́n lu àwọn míì títí tí ẹ̀mí fi bọ́ lẹ́nu wọn
21 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Iléèṣẹ́ ológun fi sọ́jà obìnrin sí àtìmọ́lé nítorí pé kọ́pà fún un ní òrùka ilérí ìgbeyàwó ní Kwara
20 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Ìṣájú
Page
12
nínú
19
1
9
10
11
12
13
14
15
19
Tókàn