BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ìkọlù àwọn darandaran
A fẹ́ rí òkú bàbá wa, bó jẹ́ eérú ẹ̀ la rí kó, ká sáà rí nǹkan sin - Ọmọ dẹ́rẹ́bà tí àwọn ajínigbé pa l’Ekiti sọ̀rọ̀
7 Èrèlè 2024
8:07
Fídíò,
'Ńṣe ni ẹ̀jẹ̀ bo Pásítọ̀ Adegboyega lẹ́yìn tí àwọn darandaran náà gún un ní ọ̀bẹ'
, Duration 8,07
6 Èrèlè 2024
Èèmọ̀! Àwọn ajínigbé Zamfara jí ọkọ ìyàwó àti ìyàwó rẹ gbé lọ
29 Sẹ́rẹ́ 2024
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Zamfara ṣàlàyé ìdí tó fi gbé ọjà màálù tìpa n'íjọba ìbílẹ̀ méje
28 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Afenifere ké gbàjarè sí Ààrẹ Tinubu: Wà ojútùú sí ìṣẹlẹ ìjínígbé tó ń peleke sí ní àwọn ìpínlẹ̀ Yorùbá
18 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
Ìgbé ayé rúdurùdu àti ìnira là ń gbé torí ìdúnkokò àwọn jàǹdùkú agbébọn
6 Ọ̀pẹ̀̀ 2023
6:53
Fídíò,
A kò fẹ́ ọlọ́pàá mọ́! Aráàlú faraya lẹ́yìn tí àwọn ajínigbé pa èèyàn nílùú Alalubosa
, Duration 6,53
3 Ọ̀wàrà 2023
11:22
Fídíò,
Ẹ gbà wá o, àwọn Daran-daran yìí ń pa ni lẹ́kún jayé, wọ́n tún jó wa mọ́lé! - Àwọn èèyàn Yewa North
, Duration 11,22
28 Ògún 2023
"Ìgbéyàwó àbúrò mí là lọ ṣe, lẹyìn ogójì ọjọ́ là tó jáde ní àhámọ́ ajínigbé"
19 Agẹmo 2023
Ọwọ́ ikọ̀ Ológun tẹ ọmọ Ghana kan tó ń kó ẹ̀kún ọkọ̀ nǹkan ìjagun lọ sí Anambra nípínlẹ̀ Ogun
17 Agẹmo 2023
Ṣé lóòtọ́ ní ìjínígbé, ìpàníyàn, ètò ààbò tó dẹnukọlẹ̀ tí rọlẹ̀ síi ní Naijiria?
4 Agẹmo 2023
Tinubu appointments: Kí ló kan ẹkùn tàbí ẹ̀yà nínú ìyànsípò àwọn tí yóò bá Ààrẹ ṣiṣẹ́
21 Òkùdu 2023
Èèyàn 160 ni agbébọn ti pa lásìkò ìjọba Tinubu, èyí burú jáì - Amnesty
14 Òkùdu 2023
Wo ìṣẹ̀lẹ̀ márùn-ún tí kò bá sọ Nàíjíríà s‘ógun abẹ́lé kejì
14 Òkùdu 2023
Ìjínigbé,ọ̀wọ́ngógó,gbèsè l'ógun tí Buhari fí sílẹ́ fún Nàíjíríà
21 Èbibi 2023
Aáwọ̀ bẹ́ sílẹ̀ láàrín Fulani àti àwọn ọmọ ìlú Iganna n'ípinlẹ̀ Oyo, òkú sùn!
16 Èbibi 2023
Ènìyàn kan kú, ọ̀pọ̀ farapa bí àwọn afurasí darandaran ṣe ṣèkọlù sáwọn àgbẹ̀ ní Ondo
25 Ìgbé 2023
6:51
Fídíò,
Èmi àti ọkọ mi ń fi iṣẹ́ àgbẹ̀ ṣoríire báyìí l'Ámẹ́ríkà àmọ́, ìmọ̀ràn wa fún ẹ̀yin ọ̀dọ́ Nàìjíríà ni pé ... - Temitope àti Olaniyi Balogun
, Duration 6,51
11 Ẹrẹ̀nà 2023
Irọ́ ni o! A kò gbé ìgbésẹ̀ láti dìtẹ̀ gbàjọba ṣáájú ìdìbò Naijiria – Iléeṣẹ́ ológun
13 Èrèlè 2023
"Ẹ fáwọn ajínigbé láǹfàní àti jí mi gbé, ẹ wá ń béèrè ìbò mi báyìí"
11 Èrèlè 2023
Tinubu fáwọn ẹbí ọdẹ ìbílẹ̀ tí agbébọn pa ní N100m, ó lérí láti fòpin sí ìgbéṣùnmọ̀mí
6 Èrèlè 2023
"Ìjọba Benue ló ní ka kúrò, tí àdó olóró fi pa Fulani 27, tí ọ̀pọ̀ sì farapa"
24 Sẹ́rẹ́ 2023
Ọ̀lẹ ní àwọn DSS ní Naijiria, TV ni wọ́n máa ń wò nígbà tí mo wà ní páńpẹ́ wọn- Ṣowore
14 Bélú 2022
Darandaran kan rí ẹ̀wọ̀n he fún ẹ̀sùn jíjí màálù 61 nìpínlẹ̀ Oyo
11 Bélú 2022
Ìṣájú
Page
2
nínú
18
1
2
3
4
5
6
7
8
18
Tókàn