BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Igbeyawo
Ọmọ ọdún 13 tí mo fẹ́ lọ́jọ́sí ti ń kẹ́kọ̀ọ́ gboyè 'Masters' lókè òkun - Ahmed Yerima
10 Agẹmo 2023
Ọkùnrin kan gbé ọọ̀ni ní ìyàwó nítorí ètùtù ọrọ̀
3 Agẹmo 2023
Ìròyìn ayọ̀! Òṣèrébìnrin, Bimpe Akintunde 'Wasila Coded' di ọlọ́kọ
25 Òkùdu 2023
Torí ìfẹ́ àwọn ìbejì ni mo ṣe kọ̀ láti sọ ohunkóhun láti ọjọ́ yìí - Damola Olatunji
19 Òkùdu 2023
Àṣírí ọkùnrin tó ní òun yóò pa gbogbo ẹ̀yà Igbo torí ìkórira tó ní sí wọn, tú sọ́wọ́ Ọlọ́pàá
16 Òkùdu 2023
'Àwọn ọ̀rẹ́ ìyàwó mi, tí a jọ ṣe ‘Hook Up’ rí, ló ń gbà á nímọ̀ràn láti kọ̀ mí sílẹ̀'
14 Òkùdu 2023
Bọ́ọ̀sì tó ń bọ̀ láti ayẹyẹ ìgbéyàwó tàkìtì, èèyàn mẹ́wàá jáde láyé
12 Òkùdu 2023
Ọmọọba ilẹ̀ Jordan sẹ ìgbéyàwó, àwọn ènìyàn ní àgbáyé péjọ síbẹ̀
2 Òkùdu 2023
Bàbá àwọn ọmọ mi ni Damola Olatunji jẹ́, a kò fìgbà kankan ṣègbéyàwó, a sì ti pínyà– Arugba
31 Èbibi 2023
Àwọn òsèré tí wọ́n ní ìdádúró kí wọ́n tó di ọlọ̣́mọ rèé…
23 Èbibi 2023
Ọwọ́ Ọlópàá tẹ obìnrin tó gbèrò láti pa ọmọ ọdún mẹ́jọ torí kí ọkọ rẹ̀ má baà fẹ́ ìyàwó míì
20 Èbibi 2023
Ìgbéyàwó yìí kìí ṣe tuntun, òkè òkun ni Olorì Akinmuda wà àmọ́ àṣà ìbílẹ̀ táà fẹ́ ṣe l'Áàfin rèé - Agbẹnusọ Ooni
17 Èbibi 2023
Ìyàwó lẹ̀dí àpòpọ̀ láti jí ọmọ bíbí rẹ̀ gbé láti gba ₦3m lọ́wọ́ ọkọ
14 Èbibi 2023
Abẹ̀ṣẹ́kùbíòjò tẹ́lẹ̀ rí lu ìyàwó rẹ̀ títí tó fi dákú rọngbọndan; Bí ọwọ́ ọlọ́pàá ṣe tẹ̀ ẹ́ nìyí
9 Èbibi 2023
Èmi àti Ooni ti mọra l'óde ọ̀run ká tóò pàdé l'óde ayé - Olori Ashley
7 Èbibi 2023
3:33
Fídíò,
‘Mo ti dáríjin ìbátan mi tó da ásíìdì sí mi lára’
, Duration 3,33
6 Èbibi 2023
'Ọ̀pọ̀ ènìyàn ló máa ń bú mi pé mo fẹ́ ẹni tó ní ìpèníjà ara àmọ́ ohun tó mú mi fẹ́ ọkọ mi nìyí'
29 Ìgbé 2023
Ayẹyẹ ìgbéyàwó ló jẹ àwọn obìnrin àsìkò yìí lógún jù ọgbọ́n láti gbé ínú ilé ọkọ lọ- Mike Bamiloye
25 Ìgbé 2023
Obìnrin ẹni ọdún 45 gbé ọkọ rẹ̀ lọ ilé ẹjọ́ lórí ẹ̀sùn pé kò mú òun lọ Saudi Arabia
19 Ìgbé 2023
Mo ní ìfẹ́ ọkọ mí Oluwo tí ilu Iwo, àti ọjọ́ tí mo ti fí ojú kàn án ni ìfẹ́ rẹ̀ tí wà ní ọkàn mi – Ayaba tuntun láàfin
8 Ìgbé 2023
Ẹ̀rọ tó lè máa fẹnu kò ọ́ lẹ́nu tí olólùfẹ́ rẹ bá jìnà réré sí ọ rèé
2 Ìgbé 2023
“Mi ò fìgbà kankan di ẹrù ìdílé mi ru Ijoba Lande, ó wù ú ló fẹ́ mi pẹ̀lú ọmọ méjì”
1 Ìgbé 2023
Ọmọ ọ̀dọ̀ àti Dẹ́rẹ́bà fi àpólà igi, bàtà àti ‘Plier’ pa tọkọtaya òṣìṣẹ́fẹ̀yìntì l'Eko
27 Ẹrẹ̀nà 2023
Ìṣájú
Page
7
nínú
20
1
4
5
6
7
8
9
10
20
Tókàn