BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Ojú ewé to wà yìí,
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ojú ewé to wà yìí,
Fídíò
Fídíò
Ìlẹ̀kùn kan ni kò padé tán, tí Kìnìún fi jáde dojú kọ obìnrin tó fẹ́ fun ní oúnjẹ - Fásitì OAU
21 Èrèlè 2024
7:06
Fídíò,
"Mo ṣẹ́ oyún oge torí ẹbí, ọ̀rẹ́ àti ṣọ́ọ̀ṣì pa mí tì, ilé ọmọ mi bàjẹ́, dókítà ní n kò le bímọ mọ́"
, Duration 7,06
20 Èrèlè 2024
5:18
Fídíò,
Wo Ìbejì àádọ̀rún ọdún tó kọ́lé papọ̀ àti aáwọ̀ tó mú kí wọn pín ilé náà
, Duration 5,18
19 Èrèlè 2024
7:13
Fídíò,
Ẹ sì mí gbọ́ ni, kìí ṣe pé mó fẹ́ ṣe ìgbéyàwó nítorí bí ara mi ṣe n bèèrè fún ìbálòpọ̀- Toyo Baby
, Duration 7,13
16 Èrèlè 2024
5:31
Fídíò,
'Mo di olùkọ́ èdè Yorùbá nítorí mi ò fẹ́ kó parun, dípò iṣẹ́ amòfin tó wù mí'
, Duration 5,31
15 Èrèlè 2024
7:28
Fídíò,
Kí ló n fa ikú àìtọ́jọ́ láàrin àwọn ọ̀dọ́ tó n jápa láti Naijiria ní UK?
, Duration 7,28
14 Èrèlè 2024
5:45
Fídíò,
'Bàbá ọmọdé, bàbá àgbà, èèyàn nlá ni Jimi Solanke tó di olóògbé'
, Duration 5,45
13 Èrèlè 2024
6:55
Fídíò,
Ẹ̀bi tani bí àwọn ajínigbé ṣe ń kọlu àwọn ọba ilẹ̀ Yorùbá?
, Duration 6,55
12 Èrèlè 2024
8:52
Fídíò,
Kò dìgbà tí a bá búra wa kí a tó kọrin tó dùn - Ààrẹ Shina Akanni
, Duration 8,52
10 Èrèlè 2024
6:51
Fídíò,
Nítorí ìpèníjà, àwọn òbí fúnrawọn máa ń kó ọmọ fún ilé ọmọ aláìníyá wa – Febishola Okonkwo, adarí Tabitha Homes
, Duration 6,51
8 Èrèlè 2024
A fẹ́ rí òkú bàbá wa, bó jẹ́ eérú ẹ̀ la rí kó, ká sáà rí nǹkan sin - Ọmọ dẹ́rẹ́bà tí àwọn ajínigbé pa l’Ekiti sọ̀rọ̀
7 Èrèlè 2024
8:07
Fídíò,
'Ńṣe ni ẹ̀jẹ̀ bo Pásítọ̀ Adegboyega lẹ́yìn tí àwọn darandaran náà gún un ní ọ̀bẹ'
, Duration 8,07
6 Èrèlè 2024
7:49
Fídíò,
Ìdí tí mo fi parọ́ pé àwọn ajínigbé jí mi gbé - Òṣìṣẹ́ Báǹkì ṣàlàyé l'Ogun
, Duration 7,49
5 Èrèlè 2024
3:57
Fídíò,
Ǹjẹ́ ẹ̀yin mọ̀ nípa eégún Zangheto tó ní í ṣe pẹ̀lú ìran Yorùbá ní orílẹ̀ èdè Benin?
, Duration 3,57
3 Èrèlè 2024
3:05
Fídíò,
Wo ọmọ ọdun mẹ́tàlá tó ń ta ''Hawaiian guitar'' sí orin Obey, Sunny àti tàkasúfèé
, Duration 3,05
2 Èrèlè 2024
7:48
Fídíò,
Ọlọ́run sọ fún mi nínú ẹ̀mí pé ẹnu Yorùbá kò ṣọ̀kan fún ìdásílẹ̀ Yorùbá Nation - Funmi Aragbaiye
, Duration 7,48
2 Èrèlè 2024
6:04
Fídíò,
Akẹ́kọ̀ọ́ tí orí kó yọ lọ́wọ́ àwọn ajínigbé l’Ekiti ṣàlàyé bí wọ́n ṣe jí àwọn akẹgbẹ́ àti olùkọ́ rẹ̀ lọ
, Duration 6,04
2 Èrèlè 2024
5:49
Fídíò,
Mi ò kí ń ṣe aláwàdà, ipá tó fi mí hàn ni àwọn èèyàn fi máa ń rò pé aláwàdà ni mí - Portable Harejan
, Duration 5,49
1 Èrèlè 2024
Ọmọọba ti ṣáájú lérí láti pa Adeoriokin tipẹ́ - Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Adeoriokin
31 Sẹ́rẹ́ 2024
6:43
Fídíò,
Àsìkò wo ló yẹ kí obìnrin bẹ̀rẹ̀ ìbálòpọ̀ padà lẹ́yìn ìbìmọ láìséwu?
, Duration 6,43
31 Sẹ́rẹ́ 2024
3:48
Fídíò,
"Ẹ́ sinmi àìmọ̀kan, àìsàn òtútù àyà kò ní nǹkan ṣe pẹ̀lú òtútù"
, Duration 3,48
31 Sẹ́rẹ́ 2024
6:59
Fídíò,
Ẹnìkan ló fi fọ́nrán ìròyìn eré ìdárayá mi sórí ayélujára tí àwọn èèyàn fi tẹ́wọ́ gbà á - Olori Sport
, Duration 6,59
30 Sẹ́rẹ́ 2024
3:20
Fídíò,
Ohun táwọn ènìyàn nílò láti kojú àwọn ìpèníjà tó ń bá Nàìjíríà fínra rèé - Ọọni
, Duration 3,20
29 Sẹ́rẹ́ 2024
2:33
Fídíò,
Báwo ni àgbà òṣèré, Joke Muyiwa ṣe l'áyà tó?
, Duration 2,33
27 Sẹ́rẹ́ 2024
Ìṣájú
Page
27
nínú
40
1
24
25
26
27
28
29
30
40
Tókàn