BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Ààrẹ Muhammadu Buhari
A kò ní ṣe ìwọ́de mọ́ torí a ti gbé ìjọba lọ sílé ẹjọ́ - Shiite kéde fáráyé
31 Agẹmo 2019
Aare Muhammedu Buhari ti setan lati yan ise fun awon minisita tuntun
31 Agẹmo 2019
Èèkànlú ní ìpínlẹ̀ Ogun lọ kí Buhari l‘Abuja torí ẹ̀yẹ tó fi dá Abiọla lọ́lá
30 Agẹmo 2019
El-Zakzaky kò fojú hàn nílé ẹ́jọ́ ṣùgbọ́n wọ́n sún ẹjọ́ rẹ̀ síwájú
29 Agẹmo 2019
Ẹni mẹ́ta gbé Buhari lọ sílé ẹjọ́ nítorí pé ó parọ́ ìwé ẹ̀rí rẹ̀ fún àjọ INEC
29 Agẹmo 2019
Kò lè ṣééṣe kí Ruga wà lápá gúúsù Nàìjíríà fáwọn Fulani- Ganduje
28 Agẹmo 2019
'Nàìjíríà, ṣọ́ra, ogun ń sọ ilé ọlá di ahoro!'
27 Agẹmo 2019
Mo ṣe tán láti kú tọmọ taya bí wọn kò bá fi El-Zakzaky sílẹ̀ - ọmọ ẹgbẹ́ Shiite
27 Agẹmo 2019
Ọrọ̀ ajé Nàíjíríà tún leè dagun tí Buhari bá fi ìyànsípò àwọn mínísítà falẹ̀ si - Onímọ̀
21 Agẹmo 2019
Fulani DaranDaran di fà kí n fà láàrin Gómìnà Ganduje àtàwọn Gómìnà ilẹ̀ Yorùbá
20 Agẹmo 2019
Ẹ wo ìpínlẹ̀ 15 tó faramọ́ ìdásílẹ̀ àbúlé Ruga
20 Agẹmo 2019
Buhari gbà wá, àwọn àjèjì ti gbàkóso ilẹ̀ Yorùbá - Ọọ̀ni figbeta
18 Agẹmo 2019
Ẹ padà sílé èyin ọmọ wa tó n ṣiṣẹ́ darandaran - NEF ti Fulani
17 Agẹmo 2019
Wá gbọ́ ìmọ̀ràn tí Jonathan fún Buhari lórí ọmọ Fasoranti tó kú!
16 Agẹmo 2019
Lẹ́tà Obasanjo: Àjálù ń bọ̀ bíi ti Rwanda, tí Buhari kò bá ṣàtúnṣe ètò ààbò
15 Agẹmo 2019
Ǹjẹ́ ẹ mọ ohun tí igbákejì ààrẹ Yemi Osinbajo sọ nílé bàbá Fasoranti
14 Agẹmo 2019
'Ẹnikẹ́ni ò lè tì mí gbọ̀ngbọ̀n láti gbé orúkọ mínísítà jáde'
12 Agẹmo 2019
Mi ò m'àwọn ẹgbẹ́ tó ń gbé ''Tinubu 2023'' kiri- Bola Tinubu
10 Agẹmo 2019
Kí l'ànfàní àdéhùn okoòwò kan l'Afíríkà, AfCFTA tí Buhari tọ́wọ́ bọ̀?
8 Agẹmo 2019
Atiku ni kò tíì dópin fún Adeleke, PDP ni àwọn gba idájọ́ wọlé
6 Agẹmo 2019
Ààrẹ Buhari jámi lórí ètò RUGA ná
4 Agẹmo 2019
Thomas John: Kí ló yẹ kóo mọ̀ nípa adelé alága NNPC tuntun?
27 Òkùdu 2019
Ayédèrú Afenifere ló bá Buhari ṣépàdé - Odumakin gbanájẹ
26 Òkùdu 2019
Aisha Buhari sàtìlẹyìn fáwọn ọ̀dọ́ tó fọnmú lórí ìyànsípò àwọn alátakò sínú ìjọba APC
20 Òkùdu 2019
Ìṣájú
Page
28
nínú
29
1
22
23
24
25
26
27
28
29
Tókàn