BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Aworan Fiimu
‘Omijé gba ojú mi kan’, Davido ń dárò ní àyájọ́ ‘Father’s Day’
18 Òkùdu 2023
Iṣẹ́ olùkọ́ kò lówó lórí àmọ́ ó ní ipa púpọ̀ ju iṣẹ́ tíátà lọ fún mi - Saka
18 Òkùdu 2023
Àṣírí ọkùnrin tó ní òun yóò pa gbogbo ẹ̀yà Igbo torí ìkórira tó ní sí wọn, tú sọ́wọ́ Ọlọ́pàá
16 Òkùdu 2023
Ninalowo kópa nínú fíìmù ilẹ̀ òkèrè, àwọn olólùfẹ́ rẹ̀ kan sárá síi
14 Òkùdu 2023
Bí Iya Gbonkan ṣe kẹnu bọ àyájọ́ èdè Yorùbá láti fi ìdùnú hàn lorí ẹ̀bùn ọkọ̀ bọ̀gìnì tó gbà rèé
9 Òkùdu 2023
9:33
Fídíò,
Ọ̀rọ̀ inú orin "Ebenezeri" kó àwọn Mùsùlùmí àti gbogbo ìjọ ìgbàlódé wá sí Cele, ìdí rèé - Kent Edunjobi
, Duration 9,33
9 Òkùdu 2023
Bàbá àwọn ọmọ mi ni Damola Olatunji jẹ́, a kò fìgbà kankan ṣègbéyàwó, a sì ti pínyà– Arugba
31 Èbibi 2023
Bí èèyàn fi màlúù ránṣẹ́ tí wọ́n bá sè é yóò kan, mọ́tò ni kí ẹ rà fún mi báyìí – Iya Gbonkan
30 Èbibi 2023
Bí wọn kò ṣe pè mí síbi àmì ẹ̀yẹ AMVCA dàbí ìgbà tí wọ́n bá dìtẹ̀ mọ́ mi – Ibrahim Chatta
30 Èbibi 2023
Àwọn òsèré tí wọ́n ní ìdádúró kí wọ́n tó di ọlọ̣́mọ rèé…
23 Èbibi 2023
Òṣèré tíátà Yoruba míì, Adewale Adeyemo jáde láyé
22 Èbibi 2023
Anikulapo,King Of Thieves (Agesinkole), Bimbo Ademoye mókè ní AVMCA Award 2023
21 Èbibi 2023
Ǹjẹ́ o mọ àwọn òṣèré bí Oyin Adejọbi, Funmi Martins àtàwọn míì tó ti dágbére fáyé?
20 Èbibi 2023
Kí Ọlọ́run dáwọ ikú òjìji dúró lágbo èrè tíátà - Odunlade Adekola
20 Èbibi 2023
8:14
Fídíò,
Ìdí tí aáwọ̀ èmi àti Tunde Kelani ṣe dá "Part 2 Ti Oluwa Nile" dúró tí mi ò tún gba owó kankan lára fíìmù náà rèé- Baba Wande
, Duration 8,14
19 Èbibi 2023
Àwọn èèyàn máa ń fi mí ṣe yẹ̀yẹ́ torí èdè ẹ̀nu mi ṣùgbọ́n bí màá ṣe sọ̀rọ̀ di ọjọ́ ikú nìyí – Murphy Afolabi, nínú ọ̀rọ̀ tó sọ gbẹ̀yìn pẹ̀lú BBC
18 Èbibi 2023
A ti na owó tó tó mílíọ̀nù mẹ́wàá Náírà lórí àìlera àwọn ọmọ ẹgbẹ́ TAMPAN - Mr Latin
18 Èbibi 2023
Èmi àti Murphy sọ̀rọ̀ ni àgó mẹ́san-an àbọ̀, ó ṣubú ni àgó mẹ́wàá àlẹ̀ - Golugo
17 Èbibi 2023
Wo àwọn gbajúmọ̀ òṣèré tó péjú síbi ètò ìsìnkú Murphy Afolabi
16 Èbibi 2023
7:28
Fídíò,
Ẹ̀yin tẹ́ẹ fẹ́ máa ṣe "prank" pa owó bíi tèmí, ẹ má dán an wòo torí adúrú ìyà tó ń jẹ mi yìí - Trinity guy
, Duration 7,28
13 Èbibi 2023
Àwọn òṣèré tíátà tó lọ́ ń fi arúgbó ara kàwé síì, ohun tí wọn yóò mú bá agbo sinimá nìyí – Tunde Kelani
11 Èbibi 2023
2:20
Fídíò,
Owolabi Ajasa rèé láì wọ aṣọ Ọlọ́pàá lórí ètò "Ṣóo láyà", ẹ wo bóyá ó Yorùbá rẹ̀ dájú tàbí ó gbé e gbági
, Duration 2,20
22 Ìgbé 2023
Mercy Aigbe ló fà mí sókè nígbà tí mi ò jẹ́ nǹkankan, Olóore mi ni – Adeniyi Johnson
17 Ìgbé 2023
13:29
Fídíò,
Kìí ṣe pé mo yí orin padà sí ti Ọlọ́run, ìyàtọ́ orin mi ti tẹ́lẹ̀ sí ìpè "Evangelist" ti mo ṣẹ̀ṣẹ̀ gbà rèé - Ebenezer Obey
, Duration 13,29
27 Ìgbé 2023
Ìṣájú
Page
12
nínú
34
1
9
10
11
12
13
14
15
34
Tókàn