BBC News,
Yorùbá
Fò kọjá sí nnkan tí ó wà nínú rẹ̀
Ìròyìn
Wò
Gbọ́
Àwọn abala
Ìròyìn
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Idibo Naijiria 2027
Eré ìdárayá
Èyí to gbajúmọ̀ jù
Okoowo oogun
Pásítọ̀ àti èkejì rẹ̀ tó bẹ́ orí ọmọdé ṣètùtù sí ṣọ́ọ́ṣì gba ìdájọ́ ikú
8 Ògún 2022
Àjọ NDLEA jó ẹgbẹ̀lẹgbẹ̀ oògùn olóró níná ní Eko
5 Ògún 2022
‘’Tí mo bá di ààrẹ! Oró ejò, Marijuana, kórópọ̀n Hyena ni màá fí pèsè iṣẹ́ fún àwọn ọ̀dọ́’’
14 Agẹmo 2022
Méjì nínú àwọn tí Abba Kyari ń bá jẹ́jọ́ oògùn olóró rí ẹ̀wọ̀n ọdún méjì he
14 Òkùdu 2022
Àjọ NDLEA nawọ́ gán ọkùnrin tó lọ́wọ́ nípa ẹ̀sùn N3bn egbògi Tramadol tí Abba Kyari ń kojú
25 Ìgbé 2022
NDLEA gbẹ́sẹ̀lé Tramadol tí iye rẹ̀ lé ní ₦5b, ọwọ́ tẹ àwọn afurasí
4 Ìgbé 2022
Ìyáwó Abba Kyari dákú nílé ẹjọ́ bí adájọ́ ṣe kọ̀ láti gba béèlì ọkọ rẹ̀
14 Ẹrẹ̀nà 2022
Ọkùnrin kan rèé tó gé nǹkan ọmọkùnrin rẹ̀ lẹ́yìn tó fa igbó yó
9 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ dákun ẹ má kó wa lọ sẹ́wọ̀n! - Abba Kyari
7 Ẹrẹ̀nà 2022
Ẹ̀bẹ̀ béèlì Abba Kyari kò ba mọ́, yóò lo ọjọ́ mẹ́rìnlá si ní àhámọ́ NDLEA - Iléẹjọ́
28 Èrèlè 2022
Ọ̀rọ̀ ìfẹ́ sọ obìnrin kan di oníṣòwò Kùkúyè tó fi bọ́ sọ́wọ́ NDLEA
24 Èrèlè 2022
Adájọ́ fi ọ̀sẹ̀ méjì kún àkòkò tí Abba Kyari yóò lò ní àhámọ́ NDLEA
22 Èrèlè 2022
Wo àwọn ewu àti ànfàní márùn ún tó wà nínú igbó mímu
18 Èrèlè 2022
Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá dárúkọ àwọn ọlọ́pàá mẹ́rin tó ń bá Abba Kyari ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn tó ń gbé oògùn olóró
15 Èrèlè 2022
Oògùn olóró tó lé ní mílíọ̀nù kan la rí gbà lọ́wọ́ àwọn awakọ̀ Onitsha sí Kano- Àjọ NDLEA
3 Èrèlè 2022
Ìgbà tí òògùn ẹ̀jẹ̀ ríru lè ṣiṣẹ́ jù rèé- Onímọ̀
16 Sẹ́rẹ́ 2022
Bẹ́ẹ̀ bá ń lo òògùn amú ǹkan ọkùnrin lè fún ìbálòpọ̀ gbígbóná, àrùn rọpa rọsẹ̀ ń bọ̀ o! - NAFDAC
27 Ọ̀pẹ̀̀ 2021
Bàbá mi máa ń sunkún torí bí kò ṣe le padà ṣeré tíátà mọ́ - Ọmọ Baba Suwe
24 Bélú 2021
Bí ọmọbìnrin tí wọ́n parọ́ mọ́ pé ó gbé òògùn olóró tó sì wọ ẹ̀wọn ní Saudi ti dara pọ̀ mọ́ NDLEA
20 Bélú 2021
Ọwọ́ tẹ èèyàn mẹ́ta tó gbé òògùn olóró sínú ọṣẹ dúdú
1 Bélú 2021
Afurasí tó gbé oògùn olóró lọ sílé ìjọsìn ní ọwọ́ NDLEA bá tẹ̀ẹ́ kó tó ké Hallelujah
23 Ògún 2021
Àjọ Anti Narcotic Cell ní India ti fẹ̀sùn kan Ndubuisi ọmọ Nàìjíríà kan pé ó gbé Cocaine wọ Mumbai
21 Agẹmo 2021
NDLEA mú dókítà àti sọ́jà lórí ẹ̀sùn títà egbòogi olóró
26 Òkùdu 2021
À ń ṣe ara wa ni Bí a bá kọ̀ láti máa lo egbòogi igbó ní Naijiria - Akeredolu
4 Òkùdu 2021
Ìṣájú
Page
3
nínú
4
1
2
3
4
Tókàn